Mo Fe Lo Si Jerusalem Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:1980
Lyrics
Mo Fe Lo Si Jerusalem - C.A.C Good Women Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin
...
Instrumentals
Talo fe lo?
Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem ilu ogo
Nibi tawon mimo gbe wa
Ti won yin Olodumare
Baba mimo mu mi de be
Ilu ogo (2×)
Opo iranse Olorun, ni won ko ni ireti ibe, opo nife aiye gba lo, opo segbe, sugbon ore-ofe Jesu nikan lole muwa debe, Baba mimo dakun mumi wole ogo
Talo fe lo?
Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem ilu ogo
Nibi tawon mimo gbe wa
Ti won yin Olodumare
Baba mimo mu mi de be
Ilu ogo
Eyin aye buburu yii, aiye ekun oun ose yii, ibi rere kan wa lorun ilu ogo, ayipada kosi nibe, ko soluwa [?] Baba mimo dakun mumi wole ogo
Talo fe lo?
Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem ilu ogo
Nibi tawon mimo gbe wa
Ti won yin Olodumare
Baba mimo mu mi de be
Ilu ogo
Lekun ogo re ti mese, oun eri kole wobe,[?] Ilu ogo, akoni gburo egun mo, orin ayo ni titi lai, Baba mimo dakun mumi wole ogo
Talo fe lo?
Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem, Mo fe lo si Jerusalem ilu ogo
Nibi tawon mimo gbe wa
Ti won yin Olodumare
Baba mimo mu mi de be
Ilu ogo (2×)
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (2×)
Oun to dara nfe adura arakunrin, oun to dara nfe adura arabirin, eyi ti ko dara nfe adura ko ba le yanju, Danieli sa gbadura ni iho kiniun, Josefu sa gbadura ni oko eru, ko seni to gbadura tojuti laye, bona re ba ruju, ko ke pe Oluwa, bogun esu ba yoju, pe Jesu re, bawon ota gbogun de, ko sato Olorun lo, adura ni ona tale fi b'Olorun soro, Iwo sa gbagbo Jesu yio mu O bori
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (2×)
Bere wo yio si ri loluwa palase, kokun a o si si pelu igbagbo, awon kan ti bere won ti gbare lowo Olorun, bi wo ba gbagbo a o fire fun o o ma beru, figbagbo bere gbogbo gbogbo aini re lowo Oluwa, so [?] ti Jesu oun labo re to daju, o n wa anu, wa sodo re, biwoba gbagbo Jesu yio da o lola
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (2×)
Alafia pupo lati sonu, a si ti jerora pupo pupo, tori a kole gbadura, ko sore bi Jesu laye to le gba wa, ore ti kin dani loba wa, alanu nii, ore aiye le ko wa sile nigba [?] Jesu nikan lore to le gbani, o fe wa, sunmo Jesu ara mi, biwosi gbagbo oun yio gbo adura re
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (2×)
aare aiye tile mu o, ti ji wahala ngba o kiri, gbadura si baba re orun, adura lo ku e kan ni sinmi, adura korin ti angeli, tiwo ba gbagbo pe isoro yio si dile
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (2×)
ore mi, mafadura sere, ninu aiye re, mafadura sere, tobafe rire gba, mafadura sere, to fe kaiye re dara, mafadura sere, bidanwo aiye de, mafadura sere, laili lailo, mafadura sere, baiye ba n nio lara, mafadura sere, baiye ba npo o loju, mafadura sere, adura ni opa kristeni lati b'Olorun rin, biwo ba gbagbo Jesu yio mu o bori
Jesu ngbo adura, Baba ngbo adura oo, ko sati gbagbo kosi gbekere le (4×)
Instrumentals