
Tire Lagbara Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:1979
Lyrics
Tire Lagbara - C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin
...
Tirè Lágbára
Tire l'agbara
Baba tirẹ l'agbara
Agbara to yọ peteru kúrò ní ninu túbú
ùn lo gba Isreali kúrò nínú òkun pupa
Agbára tó sọ àgàn d'ọlọ́mọ lo lẹ gba mi
BABA dákun ṣe o tirẹ l'agbara
tètè damilare BABA tètè damilare
mo ti sáré titi n kò dé boji o baba
mo boju w'ẹyin nkò re ni a ba f'orolo
ẹni t'ani kò ki ni leyin tún f'ẹgun ṣòwò
ẹni t'ani kò fẹ ni lloju tún f'ata senu
nkò la logboro ju ko seni ti mo le ri wisi