Keresimesi Odun De Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2003
Lyrics
[ti:Evang. Bola Are- Keresimesi Odun De]
Keresimesi odun de odun ma de o
Adupe lowo olorun to tun mu wa ri odun tuntun
Aseyi ao tun se amo dun o baba
Opolopo lajo beere odun yi
Opin re jesu omo olorun
Adupe lowo re kin se pe a fin yo won o
A fin gboruko re ga ni o baba o
Ope titi lowo olore nitori eni a se lore ti o dupe
O da bi olosha koni leru lo
Ope oloore ada yi da tan
Ope oloore a da re lare
Ope oloore adantan kari kanse
Edupe lowo baba fun ore re lori wa
Ore lori oko ore lori aya ore lori omo
Ore gbogbo ise wa ore lori gbogbo awon ebi wa
Bi ko basi jesu oba ogo
Gbogbo elebo la ba ku si
Gbogan oni wo san laba sun asi o
Aso wa iba da so alaso
Omo wa iba domo lomo
Oko wa iba do’ko loko
Ile wa iba di ile oni le
Sugbon jesu lo gba wa lo woo ta ile at iota ode
Gbogbo e wa ronu ki lo ye wa o oba ogo
Oba wa alagbara jiga jiga
Oba wa alagbala ade wure
Araba nla se gbo kiji
Oba wa lana oba wa loni
Oba titi aye o oba wa adagba ma pa ro oye
Aru gbo igba ani oba mi oba re oba gbogbo aye ooooooo
INSTRUMENTAL
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
A gbe o ga o baba A gbe o ga o baba
E ba wag be ga e ba ewa gbe ga o
E ba wag be ga
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe ga o baba
A gbe o ga o baba a gbe o ga o baba
Kabiyesi alade wura a gbe o ga baba
Ere ti a fin se ajodun keresimsi lododun
Ohun ni a ri ninu iwe John ori keta ise kerin din logun to so wipe
Nitori oloru fe araye be ge
O fi omo re kansoso fun ni
Ki eni keni ti o gba gbo ma bas se gbe
Sugbon ki o le ni iye ani pe kun
Ohun a tun ri ti oro iwe Isiah ko
Ori kesan ese ike fa le so pe
Nitori a bi omo kan fun wa
A bi omo kruin ka fun wa
Ijoba yio wa lejika re o
A o si ma pe oruko re ni iyanu
Olu da moran olorun alagbara o
Baba ayeraye omo alade Alafia
Olugbala na ni a bi fun wa la si ko keresimesi yi o
Ohun ni afi se iranti re lodo dun olorun ma fe araye to be ge
Eni to le yan da omo re kansoso fun araye
Ogo ni fun baba ati fun omo ati fun emi mimo
Ati meta lokan so so soso
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Ogo fun olorun loke orun ati fun re Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Ise bi jesu olorun ran angeli gebraili lati lo bam aria wunda
O pa de re ni galiie ti a pe ni nasaretti o
Inje bi angeli ti de odo maria
O ni Alafia iwo eni ti o ko ju si se lore
Oluwa pelu re alabukun fun ni iwo
Ninu awon obirin o
Sugbon ni gba ti maria gbo
Eru ba sugbon angeli na kiyesi
O wipe ma baru maria ooo
Nitori iwo ti ri oju rere ni odo olorun
Sa ti kiye si iwo yio loyun ninu re
Iwo yio si bi omo kun rink a n
Iwo yio si ma pe oruko re ni jesu o
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Oro yi yam aria leun oni eyi yio ma fi se lese
Nigba tie mi ko ti mo orunrin ri
Ko sese ki oborin ko loyun layi mo okunri
Otun so pe angeli ko so fun maria wipe
Emi mimo yio to wa
Agbara oga ogo ni yio sigi bo o o
Nitori ohun mimo ta o tori e bi
Omo olorun ni a o ma pe
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
A gbo pe leyin iloyun maria
Bi o ti je pe josfu penapena la bi fun
Ohun a si ma se idile dafidi
Leyin na ni ase jade lati odo ksari ogo to
Pe ki a lo pa gbogbo eniyan
Ni idile si idile
Jsoefu ati maria
Won joke lati naserti losi bethlemu o
Nigbati won lo loju ona
Osu measan maria oe ti o bi mo
Ko si se yi pada mo dandan ni ko bi tori ase orun ni
Won de bethlem aye ko si ni ile ero ,mo
Sugbon ojo kuku ti pe o ti pen a
Won ab ya si ibuje eran tara
Ni be ni maria bi olugbala wa jesu krsiti si
Omo alade wura mi o
Ohun ni a bi si inuje eran
Aye a olugbala mi ko ri ile wa si ooo
Sugbon a dupe pe am ti olugbala o
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura
Leyin ti a bi jesu olugbala tan
Angeli gabrile ti lo si odo awon oluso aguntan ni bethlemu o
O yo si won ogo olorun si dapo
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Ogo fun olorun loke orun ati fun ayre Alafia
Pe a bi olugbala fun wa
Omo alade wura