Hymns Medley Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1995
Lyrics
Hymns Medley - Evang. (Dr). Bola Are
...
Intro …
Wonyi ni díè ninu Orin
Inu iwe iyin rere ti CAC ti baba feran lati
Ma ko ninu awon isojí gbogbo ibikibi ti won ba lo lati je iyin rere kristi ati lati wa elese ri, Baba wa apostle doctor timoteu Oluwole Obadare the WOSEM executive director.
E ma ba wa kalo.
Eniti o ba wa Jesu Bo ti gba ise lori agbelebu.
Yoo ri ‘gbala kikun gbalofe tori kristi lagbara
Lati gbala.
Chorus
Eyin ayanfe olugbala npe yin
Oreofe ati Orin eje ‘yanu
O ta eje re sile fun rapada
Osi ni agbara lati gbanila.