Olorun Erujeje Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1967
Lyrics
Olorun Erujeje - Evang. Bola Are
...
prelude
Olorun mi osuba re ma re o*2
jinjin re bo aye e e e
erujejeje o
arabaribiti o
aribirabata
ara to San ni orun ti aye mi titi
ara wa, arawo, olohun harpuri o
omimi to Mi le aye kiji kiji
orogogigo baba awon eru, Adana fina Jo ooo, Adana Fina ja....
ekerin ninu ina, ina teriba fun baba, ina to Jo igbe..ti igbe ko so run Keke ina to gbe Elijah lo so orun.. owo kan soso to gbe gbo gbo aye ro, owo to mu ake jade eee ninu omi, owo gbe oku Ojo merin dide .. o ba enikan ja to wo gbogbo ara ile loju, pro igbani to gbe gbolohun un mi, alase agba to fa igi kedari ya, agboun gbe o oku a lugbulugbu o sa aki ninu ile, aki loju ogun arodede ola .. aro gege oro alafin ajobo, asu dere bi okun kinikun eya Judah eru to ju gbo gbo eru mi ran eru re toba too to Oba
beats
chorus: talalefi wee ninu Oba x2
ta lo le sakawe ologo julo emi o ro akawe Jesu ninu aye, akawe re o si lorun o too to oba, repeat chorus.x2
solo 1: se o jooba ilu yin segbe obakoba, se o jooba ilu yin ni mi segbe obakoba, awon Omo aye to Dade o, ade lasan won wo ewu kojo to Oba orun alayelu wa a, ade ina lade re too to oba (back to chorus)
solo 2: ewa wo Olori Ogun to la ina koja akoda aseda baba agba Lana ninu oku ooo okun pinya niwaju re baba ayeraye olorun ti o le keji too to oba (back to chorus)
solo 3: okun ri osa Jordani pada seyin Oke nla bori ogun, Oke kekeke bi odo aguntan wariri Iwo ile niwaju oluwa niwaju olorun jacobu ologo didan an erujejeje oba ayeraye ee (back to chorus)
too to oba aaaaaaaa
too to oba aaaa
olorun gbogbo
ofi gbogbo aye se apoti itise eee
olaninu ina koja ina o le Jo
owo inu omi omi oma ra maso
osoro ni orun aye miti
iji logun lesin oba agba oluwa mi
oloruntoto obiri aye
agbamerin lelogun won ju ba re
tototototototo oba
tottoototototo oba
olorun apostolic Orin oma se oo