Gba Aye Mi Oluwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1977
Lyrics
Gba Aye Mi Oluwa - Evang. (Dr). Bola Are
...
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Gba owo mi, Oluwa
Ki nma lo fun ife Re,
Gba ese mi fi se tire
Ki ibukun je temi, lailai
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Gba ohun adan mi,
je ki nma Korin iyin fun o
Gbe ete mi, olohun iyin re
Je kin yin o titi aye
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Gba okan mi, Oluwa
K'ero mi je ti ihin rere
Gba ogbon wa ninu okan mi
F'okan mi se ibugbe tire, titi aye
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Gba emi Jesu Oluwa
Je kin fe o ju aye lo
K'ife orun kun okan mi
Tire lemi o se titi
Gba owuro aye mi
K'osan aye mi je tire
Asale mi tire n'inshe
Mo fi sile fun o Baba
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Iwo Olugbo mi,
boya o njo ni, abi
o nba mi korin na lo
Adun re ko ni mo munwa
biko se oro iye ti nbe ninu re
Ara kunrin, ati ara birin
omode ati agbalagba
Jesu npe o loni
o nro o ki o fi aye re fun ohun
Ki o ba le dara fun o
Iwe romu, ori kejila, ese ikinni, wipe
nitorina, mo fi iyonu Olorun be yin, ara
ki eyin ki o fi ara yin fun Olorun ni ebo aye mimo
itewogba, eyi ni ishe isin yin to tona
Jesu fi emi re lele fun o
ki o ba le ye
Jesu wa saye lati wa gbeja larin eniyan ati Olorun
wo mun bi arufin, a gun logo, a sha logbe
a Da loro nitori re
Ore kini iwo fifun Jesu loni
O ki o a jowo aye re fun igba die,
ti o ni lo ni aye
Fi igbadun aye sile nitori fun igba die ni
Fi agbere to ndun mo o sile nitori olojo lede lojiji
Iwo jorun jorun ,bora bora
aje ati gbogbo awon emi okunkun gbogbo
fi eyi sile nitori Jesu dun ju be lo
iwe mattew ori ogun Odin kan
Ese ogbon odin meta wipe
nigbana ni peteru dahun, o si wifun pe
wo o, aawa ti fi gbogbo re sile,
awa si tin to o lehin
nje kini awa o ha ni
Jesu si wi fun pe
looto looto, ni mo wi fun yin pe
eyin tin to mi lehin
mini aye titun, ni igba ti omo eniyan yio joko
lori ite Ogo re
eyin yio si joko pelu lori ite mejila
eyin yio ma se idajo awon eya Israeli mejila
ati gbogbo eni tio file re sile
tabi ara kunrin, tabi ara birin
tabi baba tabi iya
tabi aya tabi omo,
tabi ile ni oruko mi
won o ri oro ohun gba
won o si jogun iye ainipekun
iwe Timothy keji, ori kinni, ese kejila wipe
nitori emi mo eniti emi gbagbo
osi damiloju wipe, ohun le pa ohun ti mo fi lelowo mo
titi di ojo na, ara ore, eema se atunwi asan mo
fi aye re to Jesu wa loni,
nitori Paul so fun wa mini iwe filipi pe
ori keta, ese keje, sugbon ohun kohun to je si ere fun mi,
a ohun mo ti ka si ofo nitori Kristi
iwo Oni fayawo, ohun ki o wa fi ere sile ki ogba Jesu loni
Tori igbaye yio kunna fun o layi gba Jesu,
aro, osan, ale re ti Oluwa ni
Nitorina so fun Jesu loni pe
tinu tinu ni mo fi aye mi fun oo
loni ni Jesu pe o, ma je o dola o
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.
Oluwa O
Gba aye mi, Oluwa,
Mo ya si mimo fun O,
Gba gbogbo akoko mi,
Ki won kun fun iyin Re.