Eyin Oba Ogo/Okan Mi Yin Oba Orun Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2006
Lyrics
Eyin Oba Ogo/Okan Mi Yin Oba Orun - Evang. (Dr). Bola Are
...
Ęyin Ôba ogo o, Oun ni Ôlôrun
Ęyin Ôba ogo o, Oun ni Ôlôrun
Yin fun isę iyanu rę ti o ti fi han
O wa pęlu awôn ero mimô l'Ôrun
O si ję imôlę wôn l'ôsan, l'oru
Ęyin angęli didan lu duru wura
Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę
Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô
Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin
Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi
Ęyin fun irapada, ki gbogbo ôkan
Ęyin fun irapada, ki gbogbo ôkan
Ęyin fun orisun imularada
Fun inu rere ati itoju rę
Odamiloju pe O n gbô adura
Ęyin angęli didan lu duru wura
Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę
Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô
Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin
Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi
Ęyin fun idanwo o, bi okun ifę
Ęyin fun idanwo o, bi okun ifę
To so wa pô mô awôn oun ôrun
Fun igbagbô ti n sęgun, ireti ti ki n sha
Fun ile-ogo t'o ti pese fun wa
Ęyin angęli didan lu duru wura
Ki gbogbo yin juba t'ę n wo oju rę
Ki gbogbo ijôba rę b'aye ti n yi lô
Isę rę yio ma yin... isę rę yio ma yin
Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi
Iwô ôkan mi (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Ôba ayeraye (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
F'ibukun fun Oluwa ôkan mi (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Ôkan mi yin Oluwa Ôba awôn ôba (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Ęni t'o ra ô pada (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Ôba iyanu (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Atayerô t'o t'aye rę rô (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Alagbara giga (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Iwô ôkan mi yin Oluwa (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Yin Baba (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Yin Oluwa (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Yin Ômô Mary o (Fi ibukun fun Oluwa ôkan mi)
Ôkan mi yin Ôba ôrun
Mu ôrę wa si ôdô rę
Wô t'a wosan, t'a dariji
Ta la ba'a yin bi rę!
Ôkan mi yin Ôba ôrun
Mu ôrę wa si ôdô rę
Wô t'a wosan, t'a dariji
Ta la ba'a yin bi rę!
(Yin Oluwa) Ôkan mi yin Ôba ôrun
Mu ôrę wa si ôdô rę
Wô t'a wosan, t'a dariji
Ta la ba'a yin bi rę!
Ôkan mi yin Ôba ôrun
Oluwa awôn oluwa
Atęręrę kari aye
Emi iba l'ęgbęrun ahôn
Ko ma to funyin rę o, Baba
Ore t'o se fun mi l'ôdun yi
Ôba nla t'o ra ęmi mi pada l'ôwô iku
Ayeraye Atayerô bi agogo
Iyin yę Ô o, ômô Mary o
Ogo yę Ô o, Alagbara giga... o se
Apata ijinlę me... ah Kabiesi t'o gba mi l'ôwô aye... O gba mi l'ôwô amôniseni
Jesu t'o gba mi l'ôwô ôta ihinrere
Oluwa awôn oluwa
Ibi o ran mi ni mo lô
Isę o ran mi ni mo ma ję o
Alagbara ninu awôn ôrun
Ah, igba t'aye gb'ogun de.... ase otitô ni Bibeli wipe
Orukô Oluwa... Ile isô agbara ni
Olododo wô nu rę o si ye
O wipe Ologun ni Oluwa... Oluwa ni orukô rę
Atayerô bi agogo... o gba mi l'ôwô iku
O gba mi l'ôwô ôta
Iyin yę Ô o... gbogbo aye mi n o fi yin Ô pata... pata
Iyin yę Ô o... Ôba ôrun
Igba t'aye gb'ogun de, Jesu wô inu ile wa
Ęrujęję, Ękun ôkô Farao
O bami lę m'agbara okunkun, gbogbo wôn fo jade pata
Oluwa awôn oluwa... iyin yę Ô o... ogo yę Ô o
Gbogbo aye mi t'o ku ma fi gbe Ô ga
Ile mi a gbe Ô ga
Ębi mi a gbe Ô ga
Iyin yę Ô o Jesu mi, Oluwa iyanu
Gbogbo ęni t'o ba m'ore Jesu k'o ba mi dupę
Ôba t'o ra mi pada l'ôwô iku
Ôba ti o ję ki awôn ôta ihinrere k'o r'ôrô sô
Iyin yę Ô Baba mi... ogo yę Ô Baba mi
Alapa jabijabi... Ara woo t'o wo iku t'ipinlę t'ipinlę
Ôrô ati iye mi... Ôba ti mo gb'oju le
Iyin yę Ô o
Ôkan mi gbe Ô ga... aye mi gbe Ô ga
Iyin yę Ô Jesu mi... ogo yę o Baba mi
Mo dupę o... f'ore t'o se fun mi
Ôkan mi yin Ôba ôrun
Mu ôrę wa si ôdô rę
Wô t'a wosan, t'a dariji
Ta la ba'a yin bi rę!
(Yin Oluwa) Ôkan mi yin Ôba ôrun
Mu ôrę wa si ôdô rę
Wô t'a wosan, t'a dariji
Ta la ba'a yin bi rę!
Oluwa o (Ta la ba'a yin bi rę!)
Ôba awôn ôba (Ta la ba'a yin bi rę!)
Jesu Kristi t'o gba mi l'ôwô aye (Ta la ba'a yin bi rę!)