Oore Ofe Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1998
Lyrics
ore ofe ohun
Adun ni l' eti wa
Gbohun gbohun re y'o gba Orin kan
Aye y' o gbo pelu
Ore ofe sa
N'igbekele mi
Jesu Ku fun araye
O Ku fun mi pelu
Ore ofe l' o ko
Oruko mi l' Orin
L'o fi mi fun od'agutan
T'o GBA iya mi je
Ore ofe sa
N'igbekele mi
Jesu Ku fun araye
T'o GBA iya mi pelu
Ore ofe to mi
S'ona alafia
O ntoju mi l'ojojumo
Ni iron ajo mi
Ore ofe sa
N'igbekele mi
Jesu Ku fun araye
O Ku fun mi pelu
Ore ofe ko mi
Bi a to gbadura
O pa mi no titi d'oni
Ko si je ki nsako
Ore ofe sa
N 'igbekele mi
Jesu Ku fun araye
O Ku fun mi pelu
Je k' ore ofe yi
F'agbara f'okan mi
Ki nle fi gbogbo ipa mi
At'ojo mi fun o.Amin