![Oruko Tuntun](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/00/21/rBEeMlfvCUSAeXy1AADAhOWm3-E846.jpg)
Oruko Tuntun Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2012
Lyrics
Olorun to da mi waiye o loni oruko amu torun wa
Adeda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayimu ire mo waiye wa
Ayisiki ire sababi temi lemi eniyan
Olorun to da mi waiye o loni oruko amu torun wa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayimu ire mo waiye wa
Ayisiki ire sababi temi lemi eniyan
Eto olorun ni emi je aseda finu fedo fife da mi
O mo mi ni iri oun gangan mi o ku si bi kan o dami dara dara
Emi amo towo adani waiye mo
Emi aseda ni wa laiye mi oju ogo re niriran mi akoko
Ipa lo fi semi sinu iyami ara nla owo oga ogo ni mi
Emi le niyan
Olorun to da mi waiye o loni oruko amu torun wa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayimu ire mo waiye wa
Ayisiki ire sababi temi lemi eniyan
Irin ajo eda wa saiye esu ota elenini eniyan duro
Ami ni bi to tele eda boni satani ta le sokale lati orun
O bu ramuramu o kan ra lon fi fi bi han eda lemo
Eni ba o waiye waiye eyan ton gbaiye gbaiye
Ema sayi bi ki ta pe aiye kun fun ibi olorun to da wa ko da wa tori ibi
Olorun to da mi waiye o loni oruko amu torun wa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayimu ire mo waiye wa
Ayisiki ire sababi temi lemi eniyan
Ti oluwa nile ati ekun re oun gbogbo to da soke epe lo da dara
Satani lo so dibi eniyan e ma se ran lowo
Ma je ko fi bi so e loruko ire n iwo je o ma gbagbe oruko a ma roni
Gbowo ma se bi alaigbo oun ta ban je la o da
Ara e gbo oruko tawon eyan pe ra won (oruko ton pe ra won)
Oruko teniyan pe ra re e gboruko to pa ra won
Oloribuku talaka ni won pe ra won (oruko tan pe ra awon)
Agan werey alare ni won pe raa won (oruko tan pe ra won)
Omugo didirin ni won pe ra won (egbo oruko tan pe ra won)
Alaiye baje atole ni won pe raa won (egbo oruko tan pe ra won)
Aletilapa ni won p’omo won oruko ton pe ra won
E o mo pe oun ta ba pa loruko o lagbara lo ri egbo
Oun ti on la koja o jowo ma fi gbera e lowo
Enikeni to ni doju ko ese kan ema fi pe loruko
Ma fepe san e pe ma ko oruko buburu
Satani lon je oruko eni la pe teni
Ati dele aiye na dandan ni ka lagun ka to yo
Sise pelu ero ire wa yo
Awon elomiran wa ni nile awon won logun odun ni gbe yawo
Won o ni le bimo won ni nile won won o nil le ko le
Won ni ilea won won kin gbo ko to ku idoju ko won lo fin pera won
Won ni aisan to se oun lo pa ya oun won tun fun loruko alarun idile
Won lo un gangan logun ebi won eda fooruko isoro poruko arare
Won nib o ti se won ni ilea won niyen
Eda e soro to dara jade ero alafia lolorun ni si wa
Ma fogun enu se ra e pa pe ra re un ti o fe je
Oruko to dara lolorun so mi
Oruko so logo leleda pe ni
Oruko to dara ni emi je
Aseda mo mi re emi a kore wale
Emi agbaiye sayo mi o ya gan lona kana
Asiki ewa wura oro ara owo aseda lemi eniyan
Igbagbo se pupo loro eda alayisan ti o ni gbagbo kole gba wo san
Ireti logun foruko tuntun alayinireti ko le kuro loju kan
Eda segun nipa oro enu re iku ati ye wa lori ahan
Ma so ahan di da ko sa ra e si wewe
Wa jere oun to ba fenu so eni to da lo saro di oun ti o gbe lena
O da ju ko ni wun se o ko fe yana lasan ni
Igbagbo ni o gba ero e sise ja ija gbaro fun oruko rere
Oruko lo ro ni
Oruko to dara lolorun so mi
Oruko so logo leleda pe ni
Oruko to dara ni emi je
Aseda mo mi re emi a kore wale
Emi agbaiye sayo mi o ya gan lona kana
Asiki ewa wura oro ara owo aseda lemi eniyan
Eda to gbe ni aiye yara pada sodo aseda
Oun lo mo di oro oun pelu lo le yanju e
Fada ni waiye se didi aiye re mura lati sat un se gbogbo
Ola ti je oruko taiye soni to ba yan mo jo ja kadi
Ore b’olorun do wo po kaiye e ko le tu
Ore b’olorun laja ko le joruko tuntun
Oruko to dara lolorun so mi
Oruko so logo leleda pe ni
Oruko to dara ni emi je
Aseda mo mi re emi a kore wale
Emi agbaiye sayo mi o ya gan lona kakan
Asiki ewa wura oro ara owo aseda lemi eniyan
Obediodomu j’oruko tuntun o j’oruko tuntun
Batholomewu j’oruko tuntun o je oruko tuntun
Jacobu j’oruko tuntun o je oruko tuntun
Dafidi j’oruko tuntun o je oruko tuntun
Maria Magdalene j’oruko tuntun o je pruko tuntun
saul j’oruko tuntun o je pruko tuntun
peteru j’oruko tuntun o je pruko tuntun
ase nipa eje do aguntan gba ire to je ini mi pada
Olorun to da mi waiye o loni oruko amu torun wa
Adeda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko
Emi lologo alayimu ire mo waiye wa
Ayisiki ire sababi temi lemi eniyan
Emi tada emi tada lowo ran olorun olorun
Emi eda emi eda mo ri oju rere oju rere
Olore ofe to ga julo
Emi ori mi ki yin se ru o lailai
Emi tada emi tada tewa togo olorun olorun
Atodo aseda o lola mi o laka we
Ati fi oruko tuntun pe mi amin
Ati fi oruko tuntun pe mi amin
Ati fi oruko tuntun pe mi amin
Ati fi oruko tuntun pe mi amin
Ati fi oruko tuntun pe mi amin