
Igbowo Eda Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Igbowo Eda - Tope Alabi
...
Alagbawi mi onigbowo, to yo mi loko iya o
Alagbawi mi onigbowo, to yo mi login
Modupe ose to san igbese mi
Modupeee ose to san gbese mi
Iwo lo yo mi loko iya ti mo kori mi Bo
Ani iwo lo yo mi loko oshi ti mo else mi bo
Oshe no dupe to san igbese mi
Oshey ooo mo dupe to san igbese mi
Alagbawi mi
Onigbowo eda