
Halleluyah Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
[ti:02 Halleluyah]
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Oju orun fun dede
Awo sanmo nipele nipele
Eru lofi ko aye o kun fun ajara
Eda o yanbo awo iwo lo dawa lawo ototo
Mo korin hallelujah si iwo ti awon torun nbo
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Mimo mimo ni won nke
Awon t’eda orun
Angeli lo wo won nfojojo fori bale o
Agbagba nke mimo solu dande aye gbogbo
Hallelujah soni ite ogo aditu
Gbogboro owo to no aye ja lati inu orun wa
Ki korin won o dake ri si olorun awon omo ogun
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Hallelujah ni won ko
Won segun aye
Kosi daru dapo oun gbogbo nlo leto leto
Ebi ko pa won ri
Be lara ko ni won ri
Kida ayo ekun rera alafia ni ite ogo
Awa ta le ke hallelujah ninu aye
Awa lafi orin isegun se a logo
A o jeri ota won o deni itemole pata
Orin hallelujah la ofi ba jesu joba
Awa ta gba la
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Hallelujah
Ni wun o ma ko
Hallelujah
Si iwo olorun mi
Orin hallelujah ni wun o ba awon torun ko o
Si olorun lailai hallelujah o
Hallelujah
Si eni to nbe lori ite hallelujah o
Hallelujah o
Si eni to logo pata pira ibere ati opin
Si eni to da aye ati orun to shaju de pada gbeyin o
Hallelujah o ooo
Hallelujah ooo lorin mi
Hallelujah ooo lorin mi
Lorin mi
Lorin mi
Yio je lojo
Hallelujah
Yio ma je
Hallelujah
Losan lowuro loru
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah