
You Are Worthy Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
[ti:01 You Are Worthy]
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
Eleburuu ike o
O ranmo nise faya ti o
Aran ni bani lo o
You are worthy
Oba to gba mi la o
Olowo ino o
Iwo nikan logo ye o
You are worthy
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
Baba awon baba
Lion of the tribe of Judea
King in his majesty
Ruler of the universe
I tremble at your feet
Lion of the tribe of Judea
King in his majesty
Ruler of the universe
Worthy of my worship
Iwo ton joba lori gbogbo aye
You are worthy
Iso aye iso emi eda gbogbo
You are worthy
Olori angeli olori orun
You are worthy
Iwo ton dari aye ati orun po
Of my praise
Iwo to da ohn ko diju ri
You are worthy
Gbongboki ooro to aye ati orun
You are worthy
Ipa nla gbogbo aye
You are worthy
Oke ati ile emi eniyan
Of my praise
Gbogbo ola
Olola to ga julo
Oloro to po julo
Ologo to ga ju
You are worthy
Oba toju gbogbo oba lo
Ijoba nibi gbogbo lori aye
Nisale ile
Alayi ni pekun
You are worthy
Baba meta lokan
You are worthy
Ajulo ton nbe nibi gbogbo eda eniyan
You are worthy
Ara orun won ri
Of my praise
Ara aye won ri o ti isale won mo o
You are worthy
Amo daju eda gbogbo
You are worthy
Ninu emi ati ara lati mo o
You are worthy
Lafi ripe iwo nikan lope ye
Of my praise
Ofi orun nikan se kiki da wura
O da orun ati aye pelu ara oto
Ebo mi ajisa aji tola
Mo gbe osuba fun ogo rabale
Ibere ogo arin ogo
Olu kangun ogo igbeyin ogo
Eni ti gbogbo aye yio pada wa bo
Kabiyesi o
Araye koba ni kabiyesi
Woni kade pe lori ki bat ape lese o
Iwo nikan ni kabiyesi
Ta o gbodo sope ki ade pe lori fun
A o gbodo pe ki bat ape lese
Lai lai
Se ade ta o mogba to de sori e
Se bata ta o mogba to wo ese re
Ti angeli gan o mo
Gbogbo awon torun njuba
Iwo nikan ni won bo o
Kilo wa semi se aye mi
Ti un oni ma bo o
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
You alone at worthy lord
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
Agadagodo emi gbogbo eniyan
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
Eni to fi emi e rubo fun emi
Gba ogo ati ola
Gba ogo ati iyin
Iwo nikan lo to si
Tani nba tun fi fun
Gba gbogbo ogo oni ba enikeni pin
Iwo nikan lo tosi
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
You are worthy
You are worthy
You are worthy
Of my praise
Iwo nikan lo worthy
Mo gbe ola fun o
Mo fiyin fun o
Mo f’ogo fun o
Mo dara po mo awon torun lati sowipe
Ose
Tori o worthy o