Yes And Amen Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
[ti:05 Beeni Ati Amin]
Amin aseda alamo
Eni ti oni a padanu
Iba o toto olu imo o
Eni ti o ni o koni nkan
Amin aseda
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Mo wari fun oba toni dida aye
Iba ma re oni gbede orun
Iwo toni gbogbo aye ni ikawo
Oti doyika to
Iba oni mo to ga ju
Eh eh baba ni baba nse
Amin aseda alamo
Eni ti oni a padanu
Iba o toto olu imo o
Eni ti o ni o koni nkan
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
O da okun
O da osa
Alara to fomi se osho
Iwo to mobi eje gba d’odo
Majemu to mu iyo ja okun iyanrin ateka aye
Oga okunkun birimu
Oga imole
Oju oni ilekun
Ogbe ibi mejeji rin laye irin ajo
Omu eda gbanu eda waye
Ibi emi ngba lo ba enikan o mo
Ajulo o
Eni ti o wa o kole mo nkan
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Eni ti oni o koni nkankan o
Majemu alayi lepin lo je
Ijinle alayi le tu wo
Irawo yi yo lalayi lonka
Beeni
Osupa nse atokun toba dale
Beeni o
Ibi gbogbo loti mi ri
Beeni
Oto lo farada orun saye
Beeni o
Osojo otun se oda e mo
Beeni
O se kan bi oye o tun se otutu
Beeni o
Eranko igbo won lo suwa
Beeni
Eweko ewebe igi iyen ose se awari tan
Eni ti ori ise e kori nkankan o
Eni ti ori ise e kori nkankan o
Eni ti orii ise e kori nkankan o
Eni ti ori ise e kori nkankan o
Ose mi dabi oun o pin mi ni ipi ti o jo teni keji
Mi o lalawu emi ni amin aseda latorun
Ada gbeyin ni mi owa fi mi joba oun gbogbo to ti ko da
O dami o su mi ni ire
Emi ni beeni ase olodumare ni
Amin loun emi lamin
Ayanmo o gbo ogun mi ni
Eda emi lofi se iranse mi
Akori iran mi oju ogo re ni
Moni imi iye e ninu
Eni ori mi kori nkankan
Eh eh eni tio ri mi kori nkankan
Eni tio ri mi kori ise olorun
Eni tio ri mi kori nkankan
Eni tio ri mi kori ise olorun
Eni tio ri mi kori nkankan
Eni tio ri mi kori ise olorun
Eni tio ri mi kori nkankan
Eni tio ri mi kori ise olorun
Eni tio ri mi kori nkankan
Amin lawa je si iwo amin
Beeni iwo loje ki aye wa o
Olorun lamin amin lon f’ami wa han
Aye ati orun lami yen
Aseda ni amin
Oro re loje kama wa
Olorun l’amin
Amin
Amin
Amin
Amin o
Amin
Amin
Amin
Amin o
Amin ati se rere
Amin
Amin ati goke
Amin
Amin ati bo lowo ogun
Amin
Amin ati di eni nla
Amin o
Amin
Ese amin o
Amin
Amin loruko re aseda
Amin
Amin loruko re aseda
Amin o
Amin ni mo se kemi bale ye
Amin
Amin ni mo se kin le goke
Amin
Amin ni mo se kappa ota ma kami
Amin
Amin ni mo se kin le din la
Amin o
Amin ni mo se kin le pada di alaye
Amin
Amin ni mo se kin le ba joba
Amin
Amin ni mo se si olodumare
Amin
Mo sope yes
Mo sope amen
Amin o
Mo sope yes
Mo sope amen