![Odara Ni'fe](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/00/21/rBEeMlfvCUSAeXy1AADAhOWm3-E846.jpg)
Odara Ni'fe Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2012
Lyrics
Efi ba fun e yin o awon angeli won yi tere ka
Gbogbo eda eniyan eyin bo ti ye
Efi ba fun e yin o awon angeli won yi tere ka
Gbogbo eda eniyan eyin bo ti ye
Korin tuntun soluwa iwo okan mi
Ema yio inu oluwa eyin olododo
Ni tori iyin ye fun oluwa
Efi ilu yin oluwa toun telo orin
Ko na soke ki baba yen ko gbo o
Nitori ile aiye kun fu anu re
Efi ba fun e yin o awon angeli won yi tere ka
Gbogbo eda eniyan eyin bo ti ye
Emi taba lareti a dariji emit oluwa gbala to segun fun
Okan mi korin iyin oga ogo
Awon angeli juba re lojojo Agbagba lorun fi ba yi ite re ka
Gbigbe lo je ogo alayi laka we
Efi ba fun e yin o awon angeli won yi tere ka
Gbogbo eda eniyan eyin bo ti ye
Mo feru gbega moyin oga ogo
Mo to ibu omi po ogba okun jo
O soro o si ti se moyin o oluwa
Efi ba fun e yin o awon angeli won yi tere ka
Gbogbo eda eniyan eyin bo ti ye
Didara nike didara labo
Didara nife didara labo
Opo lore opo ni bukun
Mo wa fi ba fun o oba to soun gbogbo ninu oun gbogbo
Didara nike didara labo
Didara nife didara labo
Opo lore opo ni bukun
Mo wa fi ba fun o oba to soun gbogbo ninu oun gbogbo
Ninu opo ife lo raga bomi ore ofe re ni mounje
Ibukun re toh po loje kemi po ninu ogo re lokan mi yo
Oun gbogbo lofi se’fe re oba oni ke didara ni o
Didara nike didara labo
Didara nife didara labo
Opo lore opo ni bukun
Mo wa fi ba fun o oba to soun gbogbo ninu oun gbogbo
Ogba mi lowo ogun idile ma r iwo mi wo larin igbagbo
Ogun ibi ati bi mi dati mole bi tota se poto won dake jeje
Ape ni ma da ni didara ni o
Didara nike didara labo
Didara nife didara labo
Opo lore opo ni bukun
Mo wa fi ba fun o oba to soun gbogbo ninu oun gbogbo
Alayinuronu o ni le dupe mi oni ya bara more je
Olori ogun to fi fe jaja ikoro lori aiye mi modupe
Ope ka sayi gun layi lopin titi aiye
Abo ti o ka lori ebi mi kogbon ki o re
Olorun to dara nike ige iwo ni m a si o
Oni ife alayi lo o di won olore mi oshe
Didara nike didara labo
Didara nife didara labo
Opo lore opo ni bukun
Mo wa fi ba fun o oba to soun gbogbo ninu oun gbogbo
Igba ti ogun dide ija oloro
Iwo iwo iwonikan lo gbee mi ro
Nigba ti eni aro di ore gbangban
Iwo iwo iwonikan lo gbe miro
Igbati eti ore gbo ogun to fese fe
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Igbati a fen i fe rere o le reri mo
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Igbati ebi wa ninu iipaya ogun
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Tabi ni jiroro yio bere eni mo
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Olufe owon iwo nikan mo ri o
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Igbati le kan roro o ti to enu gbe
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Igbatadura a’tweo o di shisha ayi so ge rara
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Igba yi po wa rari sa eniyan bi won ti jeun eni to pa ni
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Asologo salakuni irinajo aye yi
Iwo iwo iwonikan lo gbemiro
Iwo to mo oto oro to mobeere to mo ibi ti o pin si
Iwo iwo iwonikan logbemiro
A ri nu ro de olumo ran okan lo yo mi o