![Opin Aye](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/22/rBEeM1fvCY2AaRvNAACB7SWCI0Y308.jpg)
Opin Aye Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
Opin aiye ibi aiye re yi opin
Ile aiye ti shu o (ile aiye shu)
Ojo ma n lo ni ile yi eniyan se rere (see rere)
Opin aiye
Opin aiye ibi aiye re yi opin
Ile aiye ti shu o (ile aiye shu)
Ojo ma n lo ni ile yi eniyan se rere (see rere)
Opin aiye
Eni ti o lori e wa gboro yi o
Eleti ti o ku e ba mi wag be yi gbo
Owuro aiye iyen ma ti koja o
Osan aiye di irole bo oju ojo su o
Konje ma gbegbe asiko lo o su o e
Opin aiye ibi aiye re yi opin
Ile aiye ti shu o (ile aiye shu)
Ojo ma n lo ni ile yi eniyan se rere
Opin aiye
Mo wo irere aiye o aiye re bi ana bo o
Okukun subo ko lo ja ma safira
Asiko tani loke epe o fere pe o
Ke ni pata oja ma pe tata o su o
Olojo ka jo re a o fi ye si o de tan o e
Opin aiye ibi aiye re yi opin
Ile aiye ti shu o (ile aiye shu)
Ojo ma n lo ni ile yi eniyan se rere
Opin aiye
Wa gba jesu loni ore ma fi dola
Eniti wa wi fun to lowun o gba yio fi ika bo nu
Ko si ona miran to le gbe wa dele
Ta ba je adun ta je ikoro ara e je a ranti o
Iku ni o gbeyin gbogbo wa dandan ni o e
Aiye e gbo oo ko ma si ona miran mo o
Ta la gba ye ge laiye beeni mow i
Eniti tin se ibi yara kuro
Opin aiye
Asamo l’oun to sele aiye fi pa
Irokenken ni wo leyin ati ogun abele
Ede aye de loko laya aiye do lobirin po
Oun to kori soke ni josi ko ri sile o da bi idan
Ko to seju peren ile ama su o
Jesu o nip e de kelese ko woe yin wo o
Bo job a tis u patepate lo ma ku
Opin aiye de tan ka fi gbigbo se alayi gbo o
Wa ma sukun sukun (wa ma sukun sukun)
Eyi wa pada nile e ma ma se rere
Opin aiye
Ore e wa gbo e wa mo ife jesu yi o
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye
Eni wa aiye ti o ni jesu aiye asan lo wa
Eniti o se ibi yara kuru lono ese re
Opin aiye
Tori bo lowo to leyan to le fon to lekekan
Eyin wa pada ni o je kise rere
Opin aiye
Ko joko ko dara ko se ri mo eniyan ko je koko o
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye
Iwa owo re la o wo
Ateni to ni o
Eniti o se ibi yara kuru lono ese re
Opin aye
A se gbagbo ma se
E wa gbo mi oro kan yin o
Eyi wa pada nile yi se rere
Opin aiye
A je nile ijosin bi ekute e ku ife o
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye
E ji ju e gbadura tori owo te fe ko
Eniti o se ibi yara kuru lono ese re
Opin aiye
Ariran odi ati eni gbani ni imaran ton tu ile ka
Eyi wa pad anile yi se rere
Opin aiye
Oju oluwa u woyin o fere de bi ole e
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye
Bokunkun bati su a di oju olomo o to
Ibo le o gba
Eni se be yara kuro lona ese re
Opin aiye
Oro re o to ba ku le kun ma mu w abo jo
Eyi wa pada nile yi o se rere
Opin aiye
Faiye re fun olugbala to le da o gba
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye
Silekun okan re sile ma ti mo si ta
Eniti o se ibi yara kuru lono ese re
Opin aiye
Iku ori agbelebu mama je o ja sasan
Eyi wa pada nile yi o se rere
Opin aiye
Opin aiye de tan o e gboro mi e mama pada
Ojo ma un lo ni ile ye eniyan se rere opin aiye