![Mori Yanu](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/22/rBEeM1fvCY2AaRvNAACB7SWCI0Y308.jpg)
Mori Yanu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo
Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu
E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo
Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu
Ba won kan ba ku se ni gba kan laiye won
To ba d’lowo won so wi pe iyanu ni
Bi elomiran ba ya agan ri to ba wa dolomo e e
Won so wi pe iyanu loto iyanu ni
Bo ko ba dun to run geje te nikankan o f’ara pa
Eni ori re pen i ile ta ro pin t’olorun wa gbe ga
Tabi eniti o gbo ojo iku to palemo ti o pada wa ku mo
Gbogbo re lo je iyanu e iyanu
E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo
Mori yanu eee iyanu mori yanu aaa iyanu ni
Iyanu to se kenken oka mi laya titi
Ilu kekere kan wa won o toro je beeni won o la won o se agbe
Ara birin kan wa to ji se fun pe o ma bi iyanu
Eda o leru pe iyanu le ti be wa o
Okuku sele be a bi mo na bi o ti le jo iyanu
Sugbon bi o ti jo iyanu to oba ilu kan un wa kiri
Oun wa lati pa tori e o pa opolopo omo
Egbo kini ijoloju ki lo fe f’omo talaka se
B’aiye ti ri niyen eni ma ga oju a ri to
E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo
Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu
O da ba iyanu
Ise iyanu akoko iyanu
E kana ti galilee iyanu
Oro ninu tempili iyanu
Oku omo jayiru iyanu
Batholomeau afoju ko iyanu
O da ti pada fun alati iyanu
Orin lori omi akayika tan nise iyanu re
Iyanu to ga to jo emi loju ju o
Won da baraba sile amu alaiyese o ma se o
Ikan e ba kan eya ekan rere ata ti o e fi boju
Ponripori e lori igi agbelebu lo so pe o tan
Ah abi e o ri iyanu
Aro ni lara yeye iyanu
Iyanu e yi gangan iyanu
A be ni lowo ekun ti iyanu
Iyanu wo lo to eyi ka bi eniyan tori ese araiye
Iyanu wo lo to eyi o ki a somo nu tori elese paraku
Ibaje awa loun se a le se e je a bira wa
Ka ma de na pelu ako ise oba rani iyanu ni
eeeee
E e e e e e e ah ah ahaahaha o o oooooooo
Mori yanu eee iyanu mori yanu ehe iyanu
Ko si ebo ko si etutu to ma koja eni fi emi re lele
Ko tun si ife atata kan to dabi ife oluwa
Abi eni wa si aiye lati wa kese aiye gbogbo lo
Ko tun si iyanu mi ran mo o eyi ni iyanu
Oku a si sin o ji ja kadi ni sare
O gba kokoro lowo iku
Ogbe iku min ni isegun
Iku oro re da o
Isa oku isegun re da o
Ora iye araye nip o oku
O gin de lojo keta (o ma gi o)
O gin de tiye tiye lo gin de
Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo
O gin de tiye tiye lo gin de
Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo
O gin de tiye tiye lo gin de
Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo
O gin de tiye tiye lo gin de
Si ile aiyeraye gbogbo eni to yan iye ko ka lo
Ita iyanu ti ife nla le yi o
Lati odo baba eleduwa baba wa
Eni sanu gbogbo wa to fi omo re ra araiye pada
Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri
Ita iyanu ti ife nla le yi o
Lati odo aseda eleduwa baba wa
Eni fi ife da wa ti o fe ka pa run
Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri
Ita iyanu ti ife nla le yi o
Lati owo ife eleduwa baba wa
Eni gba wa sile to fi omo kan soso saw o tan ese wa
Agba iyanu to bi iyanu to eniyan un ri