![Kabiesi](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/22/rBEeM1fvCY2AaRvNAACB7SWCI0Y308.jpg)
Kabiesi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
Ka bi o o si o mo ju ba re
Osu ba re gbomo gbomo lo ro
Mo ki o ti lu ti nu didun oba to ni mi
Iba re o oba angeli
Kabiyesi o o mo ju ba re
A da ni pe o a da ni da
Apala nla to so aiye rom o juba re
Iba re o o oba mi
Gbogbo ipa gbogbo agabara
Oro godo ginya asiri orun pele aiye
Koma ma si afi were iba
Oro nla to fan oro da aiye orun
Emi inu re lo mi san to di eniyan
Aseda oba olu orun toto
Kabiyesi o o mo ju ba re
A da ni pe o a da ni da
Apala nla to so aiye rom o juba re
Iba re o o oba mi
Mo ri b a mo ri ba oba orun
Akoda aseda aditiu ni o
O da aiye da o da ohun gbogbo
Alase lori iku ati abeti lukara
Iwo loro ikoko nigbangban lo wa o
Aiye a koja orun a koja lo
Ite re lorun kinsi oni gbo ta o le ro loye
Aro meta ti do be nu to duro wa
Kabiyesi o o mo ju ba re
A da ni pe o a da ni da
Apala nla to so aiye rom o juba re
Iba re o o oba mi
Kabiyesi o o mo ju ba re
A da ni pe o a da ni da
Apala nla to so aiye rom o juba re
Iba re o o oba mi