Baba Iwo Lakepe Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2005
Lyrics
Nigeria Orile de abi ni dide nle o
Ko wa gba aare ee e
Nigeria o orire de abi dide nle o
Ko ko igboji gbare gbare gbare
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re (iwo la ke si o)
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Oju re o lami wo o baba
Orile de Nigeria ti gba ominira tipe
Afe ominira lowo re o baba
Eniti o batu sile owun lo yege
Baba jo o oluwa iwo lawa kepe ye gbawa o (ye gbawa o)
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Olowo pariwo mekunu fi igbe bo nu
To ba lo be ki laye awon omo yio tiri
Oun ti o fi fun wa o o to wa pin o kari kari
O ri ba to lon fowo ago seyin o
Baba gbawa o olu orun
Iwo lakepe iwo lo le yio ni lofin
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
To ba gbawa ko si eni a m ke ba
A kuku ti bo riosa a seleya esin gbogbo
Sibe sibe unse lo le koko
Ati sa ko lo de o baba iwo lo to wa gba ye o a sa de
Ogun idile lo lototo afowo fa lo berebe
To ba ta ro ese la o jiya a o segbe
Eleyin ju anu iwo lakepe o
Siju anu wo ori le de Nigeria
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Oh God of creation direct our noble cause
Guide our leader’s right
Help our youth the truth to know
In love and honesty to grow
And living just and true
Great lofty heights attain
To build a nation where peace and justice shall reign
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Let us all pray for the peace of Nigeria
For those who love are prosper
May there be peace and safety in your four corners
I say to you peace be with you
By the prayers of the saints Nigeria you are exhausted
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Baba iwo o lakepe
Baba iwo o lake si
Baba iwo o lakepe
Baba ti wa ma dowo re
Gbogbo omo Nigeria e gbadura fun eyin na e o se rere
Gbogbo ijo omo olorun e tori fun anu
Olori ijo ati oluso aguntan e ma se dake
Nigeria a wu re fun o o
Ere ta su fun o yio se Amin