![Afoju](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/05/52/rBEeM1f9r9eAUag6AAB6x4ulwuE151.jpg)
Afoju Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
To ba rin lokunkun ko le mo afoju ni
To ba jeun alera kole mo afoju ni
To ba r’omoje to rewa kole mo rara
Okunkun o da ma so mi so kun osan eleduwa
To ba rin lokunkun ko le mo afoju ni
To ba jeun alera kole mo afoju ni
To ba r’omoje to rewa kole mo rara
Okunkun o da ma so mi so kun osan eleduwa
Oju loba o okunkun o da eda mi gbo o
Ete wo adura araiye ka ma fopa rin Amin o
Eniyan buru ni ile aiye wo le pokun me ko fun ni
Aiye mi dowo re ba mi so mo mi bebe o
To ba rin lokunkun ko le mo afoju ni
To ba jeun alera kole mo afoju ni
To ba r’omoje to rewa kole mo rara
Okunkun o da ma so mi so kun osan eleduwa
Gbogbo abara pa e ranti abirun
E ma se ran wo e ma di ku won leru rara
Ti won to won gbe oro aiye kan pa o
To ba feni loju won tun afata senu