![Elenini Amutorunwa](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/05/52/rBEeM1f9r9eAUag6AAB6x4ulwuE151.jpg)
Elenini Amutorunwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Aditu loro yi o e o le o o le koko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa
Aditu loro yi o e o le o o lekoko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa
Eni waiye serere emu ra ogun
Awo tele yin adura o tori ko se duro wo
Ele nini un ba ni bo laiye
Ti bi ti re un la da ile aiye
Aditu loro yi o e o le o o le koko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa
To ba se e ladura ko s’ami o
To ba se e lepe ko ko o o
Eye fowo yepere mu aiye o e sora tori aiye le koko
Aditu loro yi o e o le o o le koko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa
Eni waiye se rere emura ogun
A wo tele yin adura o tori ko se duro wo
Elenini un ban i bo laiye
Ti bi ti re un la da ile aiye
Aditu loro yi o e o le o o le koko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa
Aditu loro yi o e o le o o le koko
Kori o gba ni lowo won elenini a mu torun wa