![Adake Dajo](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7uKAG6rpAAB29xXIOkE234.jpg)
Adake Dajo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Adake dajo adake dajo
Oun lo mowa o
Omi wo wa w’okan
Oun gbogbo ti an’gbaiye se
Oun lo da ojiji mo wa oo
Ipinle se aiye wa o ati opin re
Ori gbogbo koro
Adake dajo adake dajo
Oun lo mo wa o
Omi wo wa w’okan
Oun gbogbo ti an‘gbaiye se
Oun lo da ojiji mowa oo
Ipinle se aiye wa o ati opin re
Ori gbogbo koro
Enti o da oju o
Ko ni se alayi ri ran
Olu to da eti o ko le sa gboran
Ko si kor loju re
Gbangba kedere lori wa
Adake dajo Adake dajo
Oun lo mo wa o
Omi wo wa w’okan
Oun gbogbo ti an’gbaiye se
Oun lo da ojiji mowa oo
Ipinle se aiye wa o ati opin re
Ori gbogbo koro
Ka ye se si ka ye peni esin
Ka lo jawo pata
A o le gan olorun pelu igbagbo oju
Tori ko ni le gbawa
A un fi ti pa gboran si ilan esin
Ofin olorun wa da afi eyin
O po dara loju iwa won o dokan
Tegbin ti idoti o je ki adura opo onigbagbo o gba
Ojiji ti eleda da mo wa o se afihan oun ikoko o
A o ni le gba bo de fu olorun onitoun a wule tan ra re pa
Olorun alopo dakun ma wo mi pa (olorun ma wo mi pa)
Adake dajo Adake dajo
Oun lo mo wa o
Omi wo wa w’okan
Oun gbogbo ti an’gbaiye se
Oun lo da ojiji mo wa oo
Ipinle se aiye wa o ati opin re
Ori gbogbo koro
Emo to wo ijo olorun ti wa ju reke
Gbogbo aiye di iranse olorun
Ati eni baba ran ati eni ebi le de
Woli osan gangan iyen o bi rere
Ori pepe di igbale egungun
Ati alafose ati elepe
Ogo ologo de kun tori wo se agbara
Igba di be labe kola opo won
Awon ti ogun ja ti won tori ki ogun le se to wo inu ijo wa
Oma se ara kunlaso gba gi logun ton ku ogun
Abi e o ri ijo ki jesu yio de ki ni yio da o
Inje yio w aba igbagbo laiye
Adake dajo Adake dajo
Oun lo mo wa o
Omi wowa wo okan
Oun gbogbo ti an’gbaiye se
Oun lo da ojiji mo wa oo
Ipinle se aiye wa o ati opin re
Ori gbogbo koro
Eje ki a bi rawa lere
Gbogbo iranse olorun pata
Kini idahun si ibeere yi o
Oro ijoba orun ti di iwasu igba ni lenu wa
Ere wo loni so wo agba ni je ninu ise wa (e gbo)
Ere wo erewo loluwa nje
Afo wo le o ma n wo wa o
Ko ma gbe ise mi la yi lere Kankan
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo won kilo ro kiloso
To ba pe oruko won ni ijoba orun
Ta pe won titi ti o kan e o
Eniti o to ka si orun apadi
Ati eyin to mo ona ile ologo
Toba pe oruko ni ijoba orun to o ka mr sensor re kilo ro
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo won kilo ro kiloso
Oni igbagbo kari mi ete eke
Ka ti inu ijo jera wa lese dede
Adura ati awe odi si anikeji
Ife ikoko lori pepe si pepe
E o ranti o da ogbon oju ogbon lo
E o ba lako bi ibi lese ojiji
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo o won kiloruko re kilo o so
Ojo nla adajo aiye fere de
Ayi wa pada idajo a wo
Konikaluku lo ye ra e wo
Ibi to ku si gbadura ko tun se
Ko ma da di ki lo ro
Ki enu ma ba di ayi le soro
Kiloro kiloso nigbati a ba pe oruko omo eniyan
To ba pe omo o won kilo ro kilo o so
E e e e ee mo wi temi o ore ma diti
Ko ma di ona orun mo ra re
O tin fami han jesu oni pe de
Eru ibi ton be loju re lo gbe kuro
Ko ye tenu bo le soro
Lo ro nu ko pa iwa da ka si toro fun anu
Ka ju won ju se ka ju won fun olorun
Ka le joba ka wa mo won
Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun
Leyin re ohun to ku ao fi fun wa
Oun bo layi pe sa sa ro laye re
Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun
Leyin re ohun to ku ao fi fun wa
Oun bo layi pe sa sa ro laye re
Ise wa laiye yin i la ti wa ijoba olorun
Leyin re ohun to ku ao fi fun wa
Oun bo layi pe sa sa ro laye re