![Tire Ni](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7uKAG6rpAAB29xXIOkE234.jpg)
Tire Ni Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Tire ni tire ni tire ni tire ni tire ni oluwa
Mo fi sile fun o tire ni oluwa
Owuro osan mi ale mi tire ni oluwa
Emi nba je gbagbe re oo o
Gbogbo aiye mi dowo re o baba mi
Tire ni o tire ni o tire ni ooo
Gbogbo oun ti mo ni oun ti mo ni tire ni o
Oun ti mo ni tire ni o
Tire ni o tire ni o iwo mo fi fun l’aiye ati orun
Tire ni baba o oluwa tire ni
Baba iwo loni ma f’ogo won o
Tire ni tire ni tire ni tire ni tire ni oluwa
Awon kan l’aiye won f’ogo fun ere ti o lenu soro
Awon gbeke le keke atoun ija oloro
Awon kan gbeke le aworawo l’aiye won
Iwo tie mi gbeke le lemi f’ogo aiye mi fun
Tire ni o tire ni tire ni ooo
Gbogbo oun ti mo ni oun ti mo ni tire ni o
Olu da si aiye mi iwo mo f’ogo fun
Tire ni o tire ni o tire ma ma ni
Tire baba o oluwa tire ni o
Emi o le f’ogo aiye mi fun alagbara aiye
Emi o le f’ogo aiye mi fun ele bo aiye
Ko si enina baba to le b o pin ogo re
Oun ti mo je gbogbo iwo ni o o
Oun ti mo je gbogbo o iwo ni o o
Iwon ni gbogbo oun ti mo je l’aiye o
Gba gbogbo ogo o
Gba gbogbo ola re
Gba gbogbo eye (gba gbogbo eye iwo loni)
Iyin re ko ni tan lenu ko ni tan eseun
Ose eleruniyin
Gba gbobgo ogo o
Gba gbogbo ola
Gba gbogbo eye
Iyin re ko ni tan lenu mi
Ato ba j’aiye baba tire loje
Oromo ni se faya ti akan eleru
Iwo to gbe mi jade lati inu ero wa
Ofa mi joko larin awon omo alade
Ogo aiye mi olorun agbaiye lo le fu
Iwo lo to be o ju be lo
Tire ni o tire ni o tire ni o o o
Gbogbo oun ti mo ni oun ti mo ni
Tire ni o tire no iwo mo fi fun l’aiye ati orun
Tire ni baba o oluwa tire ni o
Olodumare tewo gbope mi
Gba gbogbo ogo o
Gba gbogbo ola re
Gba gbogbo eye (iyin re ko ni tan baba o seun)
Gba gbobgo ogo o (oba awon oba)
Gba gbogbo ola
Gba gbogbo eye
Iyin re ko ni tan lenu mi baba o oseun
Tire ni o tire ni o tire ni o o o
Gbogbo oun ti mo ni oun ti mo ni (tire ni o)
Iwo lo ni mi lati irun ori de ekana ese
Tire ni o tire no iwo mo fi fun l’aiye ati orun
Tire ni baba o oluwa tire ni o (oba to le mimi gba gbogbo)
Tire ni o tire ni o tire ni o
Gbogbo oun ti mo ni oun ti mo ni tire ni o
Oun ti mo je ti mo da ti mom o l’aiye iwo ni
Tire ni o tire ni iwo mo fi fun l’aiye a’torun
Tire ni baba o oluwa tire ni o