![Orun Oun Aye](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7uKAG6rpAAB29xXIOkE234.jpg)
Orun Oun Aye Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e
Didara orun oun so togo re o olorun
Ewa re to yi aye ka n so togo re bo ti po to
Gbogbo eda eranko at’ewebe n yin o o
Ise owo re gbogbo lo n keyin le won yin o o baba
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e
Ola lo wo laso ogo lo fi pa kada orun
Ika ese re o n han l’ori apata
Esin re n fogo yan l’ori awo okun o olola nla
Kini o waa se mi ti n o jokeleyo
Ti n o ni le juba re oba
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e
Gbogbo emi inu mi o n yin o yato olorun mi
Iwo to mu la ina koja to fi mumi goke
Kini mba fi fun o
Kini mo tosi ninu oreofe ti mo rigba lodo re
Oba ye mida majemu lati nu’mole
Oro ye ye osise
Oba ti ki n dale oro ore
Iwariri ni n o fi juba re
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e
Orun oun aye kun fun ogo re
Orun oun aye kun fun ogo re
Egbegberun awon irawo kede ogo re
Kinni o waa se mi ti n o ni le maa juba re o e