Abo Mi Kodara Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Alagbara aiye aiye a tan oo oo
Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo
Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san
Olojo di e laye ma gba on akan kan
Alagbara aiye aiye a tan oo oo
Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo
Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san
Olojo di e laye ma gba on akan kan
Ofe fe laiye asan ma je o wo e leje
Igba o lo bi orere ofo mu sa bi oshey bi
Ofada gbara o keya lomo
Oti pa ida pani o gba ida ku o
Alagbara aiye aiye a tan oo oo
Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo
Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san
Olojo di e laye ma gba on akan kan
Mo fe di mimo mo fe di olowo
To ri e osun orun waju po moti ipako
Eniti o jaiye jeniyan apadi lo je won
Ni o je won mourn, ki esun ko se ore re titi
Ko ni pada yan e je
Alagbara aiye aiye a tan oo oo
En loni e gbo awon ti o se ano wo si mo
Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san
Olojo di e laye ma gba on akan kan
Aseda to da wa kin kan ju
Pele tu lo da aiye lo da orun
Ohun lo fi pele se won lona ara
Eni ba kan ju yo sanu ninu ise owo re o
Ohun ami sare le kin tele ni de orun
Ewo auye ke ro ni
Alagbara aiye aiye a tan oo oo
Eni loni e gbo awon ti o se ano wo si mo
Igba loni gba lo bawo losi re, a be da su yo se san
Olojo di e laye ma gba on akan kan
Bi araiye ri o bi ero ano wo o,
Shey ni won gbelu e
Mo pe oloro ni o jinijini to fin mu eniyan
Pelu eru igba to se toto koni enikan
Eda aiye pata lo ni igba ti o lo
Igba ti e mattan o di asiko olorun
Ogolonto to le oba to ri gbajumo odaju
Ko ni lo laiyi jiya ema gbagbe
Edumare to iye na loni gun
Eba je ki beere ki lagabara temi
Oba je ki abeere ki agabara teri
Ahon lagbara elomi ran wa
Ton fi enu ba ikan je, alagbara
Owo lagabara elo mi ran wa ton fi da ikan ru, alagbara
Se inu lagabra tire to koro bi ijogbo
Ti o ban binu si aniyan wa wo bi ko subu
Ttabi koku, Alagabar
Agbara ati sunmo eniyan bat i eni je
La gbara elo mi, agbara
Agbara e teriba lati jale, tabi lati seka
Ese lagbara elomiran wa ton rin lati se bi
Ipo lagbara elomi ton fin ni omo lakeji lara
Ema je a gbagbe pe ile aiyema tan o
Bi aiye se lon ni eniyan kuro
Igba egberun onigba
Igba igba onigba o
Gbo gbo igba loni igba pata
Asiko re lo serere,
Bere ni ibikan kp pari e si bi kan o
Eniti o ni eni dandan a to kuro o
Arugbo se omidan ri, igba lon lo
Ohun to ma tan, oma tan
Ko ma ba aiye mi je
Omo ti ama na to ma tan
Ko ma baiye m je
Ile ti ama ko ti a ma gbe ta ma ku
Ko ni ma aiye mi jeoo
Golu ti a ma nit i o pa mi
Ko ma baiy mi je
Okiki ti a ma ni ta ma ku
Ko ma baiye mi je
Buruji to ma tan to ma tan to ma tan
Ko ni baiye mi je, olorun gba mi o
Ipo ti ama de ti elomi ran ma joko si be
Ko ma baiye mi je
Ewa to ma ni tama ni
Ti o pada di arugbo oo ko ma ba aiye mi je
Ola ti a ma nit i a ma nit i a o tun fi si le
Ko ma ba aiye mi je
Ohun gbogbo lo ma tan lo ma tan
Ka ma tan ara wa je