Je N'Lenu Ope Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Ke niyan to ko go ja oju ri
Beniyan ba lola e bi lere
Pe bawo ni sale oro enu a bo
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Gbogbo oun tolorun da daradara ni
Sugbo tibi tire ni a dale aiye
Eda ko se lala laiye yi
Atilo atibo mi laiye o jesu je ko jasi rere
Igbeyin aiye elomiran oju a pon
Elomin le wo titi ko ma yio
Titi iku yio fi pa abi eri
Mo fe dogun mo fe dogbon nile aiye baba je lenu ope
Oun olorun ba ko ko seni to le baje
Koseni to fowo bojo ko ma yo
Ninu igbajo ni mariwo tiun se so
Oba oke maje kenu ope mi ko kan o laiye
Gbogbo oun ti mo ba se lowuro atisan mi to ba dale jen lenu ope
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Ati lo atibo nigbeyin semi len tin dupe o baba
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Ati olowo lowuro elomisan kon ni san ladawon se debawon egba be
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Baraiye ba binu beleduwa babinu aiye ope a yo fun mi o
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Ero olorun s’eniyan didara ni ye ipa aiye ko ni ka gbogbo wa e amin o
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Loruko jesu lala wa nile aiye o je a lenu ope e
Lala mi nile aiye o edumare jen lenu ope
Oluwa se temi nire mo be
Oluwa se temi
Eniyan lo so ba gba dogun igba o wule gun momo o
Oluwa se temi
Sugbon ko ri fun eniyan gege bi ero okan re si omo lakeji re
Oluwa se temi
Oluwa ko se tawa ni re mo be
Oluwa se temi
Oluwa se temi nire mo be o
Oluwa se temi