![Jesu Lagbara](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMlfyA-mATSFGAACJDIBop5M911.jpg)
Jesu Lagbara Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Bi mo ba sun bi mo ba ji iwo lolorun mi o o o
Bi mo ba lo bi mo ba bo iwo lon so mi o o o
Un ba fi gbogbo se ahan ko to lati yin o fore to se
Anu re lori mi oju iyepe okun lo uhm uhm uhm uhm
Ogigba ti gbelese mo de latu yin o o o o
Ara to da fun mi je ka r’aiye mo pe alagbara ni eh o uh o
Gbogbo ebi ore lo foro mi sa ri ko gbon
Pe oun lagbara to gba ni un laiye
Eniyan ba mi ka lo ka jo yin tori alagbara ni
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Eni ta bi lai labawon ko se Kankan rara
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Agbani la gba tan olotito oba iyanu ni
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Agbara laiye ati lorun jesu lafi fun o
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Oun lalagbara gbogbo aiye lomo
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Oun lalagbara gbogbo aiye lomo
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Mo le fo soke kin tub ere mole kin ma jo o o
Mo fegbe otun yin,a fe gbe osi yin baba o ah ah
Ma rababa ma dobale tori alagbara ni eh eh
Oun to se fun mi o jo mi lo ju o o o
Mo si konge ayo mi kun ona mi wala
Eniyan bami ki bami yin ore re po tori algbara ni
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Oku ojokeyin ni lazaru jesu lo gbe dide o
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
O pari ise igbala wa lori agbelebu
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Oti fun wa ni ireti o si ile ologo
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Ofoju kan sakewu lori igi igbala wole re
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Yin yin yin yin Yin yin yin yin
Gbe ga gbe ga gbe ga
Bere mole ko yin yin Bere mole ko yin
Fo soke ko yin Fo soke ko yin
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo
Xxxxxxxxxxxxxxx
Jesu lagbara gbogbo aiye lomo