![Alabarin](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMlfyBBiAULrNAACaWQmkGQ0755.jpg)
Alabarin Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Obi eni tomo toko taya won o le bani rin rinye
Oni bi ti won o rin de ti o fi su won
Alagbara nikan lo le bani rin rin ajo aye ti ko ni su ti ko ni re
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Ore alanko aye ko le ban iwo titi
Eni aso duro lorun re ni won ma jowu kiri
Owe yourba logun omode kole sere fogun odun mewa o
Jesu ni kin su ti kin re o
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Alaba je aye yi ko le ba ni je pe titi
To ba je de bi kan a pada ni a la ba je won kin ba n iwo nu la si gbo rara
Sugbon ko ni su jjesu ko de ni re
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Jesu wa bami rin irin ajo aye mi baba
Olorun ti kin fi se re sile fenikan se
Momo pewo lole mu rin rin ajo laiye mi ko se
Ko de ni su o ko de ni re o
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni re
Alabarin aye yi ko le bani rin
To ba ti rin de se ni yo su
Jesu nikan lo le ba ni rin rin ajo aye ti o ti ko ni su ti ko ni r