![Aye Le](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMlfyBBiAULrNAACaWQmkGQ0755.jpg)
Aye Le Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Aye le o ibosi o aye dori kodo ko ye ni mo
Ibo la mi lo eniyan o su ni ye
Ibi sa pa magba ko ye niyan
Aye le o ibosi o aye dori kodo ko ye ni mo
Ibo la mi lo eniyan o su ni ye
Ibi sa pa magba ko ye niyan
Eniyan e so funmi ibo la lo gan e
Lomo de ategba a wa deni ti o gbon mo
Beni kan ba se rere elomiran a se bi
Onse mi on gba mi la se kun dupe lowo eni to se ni
Iberu olorun ko si lokan aye mo
Ibosi tan le kan ke ko je ka mo pe iya ni
Ibo la mi re o
Aye le o ibosi o aye dori kodo ko ye ni mo
Ibo la mi lo eniyan o su ni ye
Ibi sa pa magba ko ye niyan
Ayi mo ye igbeyawo lo ti fori so pon
Awon to fe beer won ti doni ikorira
Osi lon je tani mo ri owo lonje mo ba e tan
Ise so poo mo birin da lagbere okurin yaw o ka
Alafowo fa ari se ma se ole lo bere be
Baba o jo mo loju o to ju suni e je ka gbero ara wa pa
Abi bo ti ma lo re o aiye e da mi loun
Aye le o ibosi o aye dori kodo ko ye ni mo
Ibo la mi lo eniyan o su ni ye
Ibi sa pa magba ko ye niyan
Opo omo ti so obi di oni rewesi
Olukoni ati akeko ti di ota ara won
Tori aja to yo ko le abala yi yo sere
Awon to wa kawe ti won o ri sese nko
Opo agbani sise ti o ba ba ni sepo ko ni gba won si se
Ese wan gori ese lo
Aye jese tan won tub u ese jade
Iborisa ati oso laye fi jeun ori olori apa alape odindin omo tuntun
Aboyun dawa ti nigboro enito wo moto elero jade nile
Ole ma pada waile mo ibi ikoko ara won di fifa bo
Ka boni lowo iyen tun dogun ko wa seni to se fokan tan mo
Ara aiye igba wo la fe seyi da e gbo na se sa mama wo ni
Aye le o ibosi o aye dori kodo ko ye ni mo
Ibo la mi lo eniyan o su ni ye
Ibi sa pa magba ko ye niyan
Gbogbo ijo olorun ni gbogbo agbaye oro yi kan wa o
Ema lju sile ki talu bo ko wo
Eje ka gbadura bosen lo yi ko sun won
Iwa Alafia orile ede yi gbodo je wa logun
Eje ka je apera rere wa lo ye ka beere
Orile de wa adura komo lori
Kolorun gbase lowo esu to fogun won o
Gbori re ma gbabode mo ki o gba atunse
Ile Nigeria beere sini se rere
Orile de wa adura komo lori
Kolorun gbase lowo esu to fogun won o
Gbori re ma gbabode mo ki o gba atunse
Ile Nigeria beere sini se rere
Ilu ibile mi ibi a fori mi sole oya ma kore ran mi
Ori le ede wa beere sini se rere
Ori gun merin ile yin oya beere sini ma gboro oluwa se rere o ee
Ile Nigeria ki o gba atunse
Ese to ti lere sa jesu dariji ni ire ma bo sun wa bo
Ori le de wa o beere si ni se rere
Gbogbo eniyan to be nibe e ma gba Alafia olorun ire ko wole wa
Ile Nigeria ki o gba atunse
Gusu ariwaila orun iwo re oya ma ko ibo di mo so o
Orile ede wa beere si se rere amin o beni ko ri
Keni keni ma se di o lowo amin ile Nigeria ko I gba atunse