![Maiwaisinmi](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMlfyBBiAULrNAACaWQmkGQ0755.jpg)
Maiwaisinmi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Christiani ma ti wa isimi o gbo bi angeli e tin wi
Larin ota ejo ikoko paramole lo wa ma sora ma jagun lo
Christiani ma ti wa isimi o gbo bi angeli e tin wi
Larin ota ejo ikoko paramole lo wa ma sora ma jagun lo
Akoko ko yi to o ku die ile aye ogun ni
Eni to jagun to segun oun la pe lakoni eniyan idiju ko re fun gba die ni o
Tera mo adura re
Christiani ma ti wa isimi o gbo bi angeli e tin wi
Larin ota ejo ikoko paramole lo wa ma sora ma jagun lo
Lara eniyan mi ni ika eniyan wa
Opo eniyan to gbara le lo ti ye o kale ara
Ofe tesi waju ko sona ogun be ni wa o tun be leyin
Tera mo adura ofere bona
Opo ta pe la segun won ti jagun ri beeni
Jobu je tire o segun jabesi gbadura o segun
Opo ogun lo dogu ko josefu afi gba to segun o
Gbogbo ebi josefu lo teriba fun ma gbadura
Christiani ma ti wa isimi o gbo bi angeli e tin wi
Larin ota ejo ikoko paramole lo wa ma sora ma jagun lo
Boya o ti le ti su o o fe pada ma pada rara kesu ma fi o se yeye
Awon to duro de oluwa ni yo tu agbara won se o
Oju boro o se gbomo lowo ekuro o beeni
Eni to toni gba loye ka foro lo ope ni shola kin peni fun ya je
Ba olorun soro lori eni ko si duro je tu ju ka oluwa ti segun aiye
Christiani ma ti wa isimi o gbo bi angeli e tin wi
Larin ota ejo ikoko paramole lo wa ma sora ma jagun lo
Alafia sa niwon bi a ti le pa re o bi a tun sumo re lon ji na si
Agbero a ti duro si bi a ba se ba a o pada on a eburu kan to wa ni jesu
Alafia sa niwon bi a ti le pa re o bi a tun sumo re lon ji na si
Agbero a ti duro si bi a ba se ba a o pada on a eburu kan to wa ni jesu
Satani ti padanu ire gbogbo na owa du ramuramu boya a reniti o kolo
A je gbodo un wa eni kura ara e sora o di jesu mu o sa gbekele o jara
Alafia sa niwon bi a ti le pa re o bi a tun sumo re lon ji na si
Agbero a ti duro si bi a ba se ba a o pada ona eburu kan to wa ni jesu
Ona eburu kan to wa ni jesu o jare
Onde bante ifupa ko to gbani laye ese yi
Ranmti a ti fun wa ni oruko to ju gbogbo oruko lo patapata
Pe ni oruko jesu ki gbogbo iku ma wole o
Egboro kini hun ati ejo nla la o fese te mole
Ni pa se adura gbogbo ogun la ma se
E ko seni to fowo oun itule to boju woyin to ye fun ijoba orun
Di jesu mu sa gbekele yio gba o ore mi
Alafia le ma sa o ku die wa le ba tera mo
O kan somo loku beeni a ko ni sin mo ku re
O fere debe na o ma ti wa isimi christiani
Bo pe boya akololo y ope baba o tera mo
Sofun jesu nikan a gbo a gbo o
Abi eni to da eti a le salyi gboran o se wo
Eni to to ni gba lo ye ka foro lo fi lo a gbo
Ani ko sona e buru miran to yato fun jesu
Ma pada ma boju woe yin a gbo tire o jare