![Ji Irawo](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMVfyBDKAdnuKAACaWQmkGQ0667.jpg)
Ji Irawo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Ji ji ji ji irawo (ji o irawo)
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (eleduwa loni irawo a d’aiye ba)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o
Ji o irawo ma sun a sun para
Ji ji ji ji irawo (ji o irawo)
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (gbera nle ko dide)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o (irawo ni o o)
Ji o irawo ma sun a sun para
Ologo di de ma sun a sun pi ye
Ibi pataki lo fi wa l’aiye o
Gbe oruko olorun ja l’aiye re
Dide tan imole
Ye fi ojoju mo po se si aiye re
Ma fi enu se akan ti si aiye re
Gbadura ma se se ole rara
Ma sun le ogo mo le
Ji o oooo irawo ni o ji o
Ji ji ji ji irawo (ji o irawo)
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (oun lo mu o wa si aiye)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o
Ji o irawo ma sun a sun para
Ji ko we bi ologo
Ko wo aso bi ologo (wo so bi ologo)
Ami I da ni loju wa pe o se rere (beeni)
Ma fi aiye ti esu ese si le jiiii
To ba je toro to ri shi ri shi ti a ti so si aiye re ni
Awon ti o se to ye ki o sure fun o won ti fi o re
Ogo eniyan mimo
Eniyan o ni mo tin ja o bi pe bi
Gbadura ki olorun sure funoooo
Ki oo se
Ji ji ji ji irawo
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (oun loni irwao a d’aiye ba)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o
Ji o irawo ma sun a sun para
Ji ji ji ji irawo (ji o irawo)
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (mo ni ko ma sun pa ra)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o
Ji o irawo ma sun a sun para
Ji ji ji ji irawo (ji o irawo)
Eleduwa lo ni irawo a d’aiye ba (gbera nile ore mi)
Eleda to da oo da irawo re ko gba gbe re o (ma wo egan ti a ti kan e se yin)
Ji o irawo ma sun a sun para