![Loke Erupe](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2E/rBEeMVfyBDKAdnuKAACaWQmkGQ0667.jpg)
Loke Erupe Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Gbogbo eni ton be lori oke erupe e gbo o
Ojo melo la o lo laiye ti a mi wo ewu erin
Irin ajo omo eda iku ni opin re
Asan ni ile aiye inu re mofo
Lasan laiye o fi ogo afere han mi
O fa mi mora kin le je omo aiye
Oun won yi o ko ni bori mi
Ki mi kima foya
Ki mi laya kin ma beru
Awa hun wa ore ofe ewu kan soso
Gbogbo eyi ti o ku dabi ojiji ti o koja
E je ki a wa eyeee ogo ti orun tooto
Orun lo ja ju oo so hun lo ja ju
Bi a ba pa danu jesu a pa danu oun gbogbo
Iro ru isimi o igbala ti ko ni pe kun
Alafia to ye ki awa ni lati wo orun rere
Ani ni ile ologo ki emi ma pa danu
Ema ma je ka gbagbe o
Pe ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Bi olu ka luku ti na ja lo ja
L’akoko un lo ile un su o
Bi Ile ba ti su dan dan ni kare ile o
Ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Ema ma je ki a gbagbe o
Ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Bi olu ka luku ti na ja lo ja
Akoko hun lo ile un su o
Bi ile bati su dan dan ni kare ile o
Ajo laiye yi orun ni ile wa
Igba kan nlo igba kan nbo
Bo kan ba ro’kun ro’sa
Fori fu Elebute
Bi odo gbogbo ba san titi
A san sinu okun o
Wo bi atin wa la dari lo
Bi ape laiye o ba ape o iku na lopin oun gbogbo
Eniyan roo oo roo ee
Ema ma je ki a gbagbe oo
Pe ajo laiye yi orun ni ile wa
Bi olu ka luku ti na ja lo ja
L’akoko un lo ile un su o
Bi Ile bati su dan dan ni kare ile ooo
Ajo l’aiye yi orun ni ile wa
A fi ile le fun eniyan lati ku le tan ooo
Leyin re idajo ni
Talenti ti a fi fun o nko
Omo ti a fi fun oo
Iwo a da ni loro
Alagbere
Gbogbo awu iwa ibaje
O di dan dan ao se isiro
L’ojo ikore oluwa
Epo lo ba je tabi alikama
O’nbo wa san ooo
Fun olukuluku gegebi ise owo re o
Ema ma je ki a gbagbe o
Pe ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Bi olu ka luku ti na ja lo ja
L’akoko un lo ile un su o
Bi le ba ti su dan dan ni kare ile o
Ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Ema ma je ki a gbagbe o
Pe ajo l’aiye yi orun ni ile wa
Bi olu ka luku ti na ja lo ja
L’akoko un lo ile un su o
Bi le ba ti su dan dan ni kare ile o
Ajo l’aiye yi orun ni ile wa