Mo Ti Ni Jesu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Mo ti ni jesu mo ti loluwa
Mo ti ni jesu mo ti loluwa
Eru iku ko bami mo isa oku ko deru bami
Tori ti ni jesu e ee
Oba to da mi lai gba be tele mo yin o
Iwo ni olorun mi eleda mi to da gbogbo wa
Iwo ni olorun mi eleda mi to da gbogbo wa
Baiye ba b’ogun besu ba sa mi
Baiye ba b’ogun besu ba sa mi
Oluwa ma se ko mi sile yara lati ran mi lowo
Baiye ba b’ogun uhm uhm
Nitori enu awon elegan ya sile simi
Jehova gbadura mi ma se sami ti kuro lodo re
Jehova gbadura mi ma se sami ti kuro lodo re o
Okunrin sumo jesu obirin sumo
Okunrin sumo jesu obirin sumo
Ma waiye mo ra ma je su ofokan re se’le
Ara mi sunmo jesu eheh
Opo eniyan sato olusi feri won o mo pe
Oluwa mi ju gbogbo aiye ati orisa re lo
Oluwa mi ju gbogbo aiye ati orisa re lo
To ba mi se ka to si tun lara
To ba mi se ka to si tun lara
Loja wo nu re kole gba dariji
To ba mi se ka ah ah
Nitori oju oluwa kan sa layi sododo
Eti re shi si si igbe awon to pe ni ona ododo
Eti re shi si si igbe awon to pe ni ona ododo
Ejo mi belorun aro dake
Ejo i belorun aro dake
Ejo belorun aro dake
Ejo belorun aro dake
Eyin araye ni mo ke si aleyin arayae ni mo bawi
Ke mi a sora nitori orun ni
Jesu yi jaya fun gbogbo agbaye o tori awa on gba awe
E ma se jo san tori bi pe ba dun ka le ba joba
Aro dake
Ejo mi belorun aro ka woleri
Ejo mi belorun aro dake
Alokuta to mo le koo o ti wa di Pataki igun ile
Be o ba gbagbo eni mo jesu ni yi ojo gun orun
Ejo mi belorun aro ka wopoyin
Ejo belorun aro dake
Ejo belorun aro sunkun
Ejo belorun aro dake
Iku jesu lori agbalebu e ma se je ko ja sasan
Tori elese ni jesu ku fun o
Bi e tin se te o jawo be len ko mo agbelebu o uhn
Lojo idajo ke ma ba jebi ni
Aro dake
Ejo belorun aro dake
Ejo mi belorun aro sukun
Ejo mi belorun aro dake
Ejo mi belorun aro kawoleri