![Ki I Koni](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/01/09/4c40a45b6afc4634a7e40de12c28431b_464_464.jpg)
Ki I Koni Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Ki I Koni - Tope Alabi
...
ebi le koni,kara koni
kegbon koni,kaburo salo
iwonikan lemimo o tikii koni o
ebi le koni ,kara koni
kegbon koni kaburo tun salo
iwo nikan lemi mo o ti ki i koni o
o kii koni o oo koni o
o kii koni ooo ko yan
o kii koni ooo koni
o kii koni o
thank you lord Jesus
toba JE pe o lowa ni asiri wa o titu
gbogbo ohun ta n bo titi ni o wa
ohun gan mo pe packaging la n fisi
sugbon packaging ti wa ko lo je ko fine
packaging ti e loje ko make sense
to ba ele shi packaging yen
ah, okere de gba alate o kawo leri niyen o
olorun tikii ko eyan o
Baba le koni ki ya koni
kegbon koni kaburo salo
iwo nikan lemi mo oo ti kii koni oooo
o kii koni ooo,koni oo
okii koni oo Jesu I koni o
iwo nikan lemi mo ti kii koni ooo
koni ooo koni oo (JE n gbo e)
koni ooo koni o eeeeee
koni ooo koni oo ti kii koni o
o ki koni ooo koni o
o kii koni ooo koni o
o kii koni o koni o
o ki koni ooo koni oo
to ba JE bi aye ti n gbani segbe ni
ti won n ko yan ni lo ma shey nko yan ni
eni e ko ti po nle gan o kii ko yan ni o ki ko yan ,o je ko awon ti e oni majemu ayo ti kii da majemu
agbe o ga loni ashey o loba
kii sheep ati Dade fun o
sugbon afope wa de o lade
kii shepe a to firukere le o lowo sugbon a fi ope wa firukere le o lowo
kishepe ato bee tale fi ewe akoko de