![Aye](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/04/11/a120e354835c45349dd908fc5e95998f_464_464.jpg)
Aye Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Toju Inu - Tope Alabi
...
Ohun ti eda ma je laye inu e lo wa oo
Ibi ti eda ma de laye inu e lo wa oo
Eda o le mono ko pon ko gbe ladugbo dani
Ero to n lo sodo ni o ponmi bo wa le
Toju inu ee
Toju inu e
Toju inu e ooo
Toju ero re ooo
Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba
Toju inu e toju okan re o toju ero re oX2
Akaba ti eda ma n gun laye inu e lero wa oo
Eda ti o wo aso alari inu e dan
Alainiran to n Ki Oba ni loro kole joye layilayi
Tori eni ba moyi wura la mi n ta fun
Toju inu ee
Toju inu e
Toju inu e ooo
Toju ero re ooo
Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba
Toju inu e toju okan re oo Toju ero re X2
Awujo awon ton banri awa o lati inu e
Eyan meji ko le rin papo lalai se pe won mowo ara won
Obun ti o bo mi osun kan ra to n wa pe alagona ni werey o ye ko mo p’ ologini ri omo ekun ni
Toju inu ee
Toju inu e
Toju inu e ooo
Toju ero re ooo
Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba
Toju inu e toju okan re
Ero ti eda n ro laye lo n gbe won rinrin ajo ototo
bokan da ba buru laye aye e shamalamala agbonri ri ewa bo n lono ijapan wa koto sona fun
sere taja f’ogun odun sa fanda leshin fin yan
Koto ti ‘japa wo sile na li o ni je ko lo oo
Odun ti kiniun ti peran je seni Aja sha yan
Ma sho oooo ero okan re
Be positive all the time bo ti wun ko ri
Ero inu dori ayanmo kodo keya sho oo
Opo ohun ti eda n ro oun bawon ri irin ajo
Eni ro rere o ti se o
Eyan to n ro ika o ti se
Opo ohun ti an ri laye eda ero won ni
Toju inu e toju okan re o pelu ero re
Toju inu ee
Toju inu e
Toju inu e ooo
Toju ero re ooo
Ero gbogbo ero gbogbo ke gbo oo ke gba
Toju inu e toju okan re o toju ero reX2