![Toju Inu E](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/04/11/a120e354835c45349dd908fc5e95998f_464_464.jpg)
Toju Inu E Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Jesus Reigns - Tope Alabi
...
Jesu oni joba
To ni joba
Eni ti gbogbo ijoba nbe lejika re
To ko gbogbo ijoba lowo
Kabiesi o
Hallelujah Jesus reigns
He reigns
He reigns
Hallelujah Jesus reigns
Oun joba Lori aye gbogbo x2
Hallelujah o
Jesu joba o
Olowo ori aye de
Kabiyesi awon ijoba
Imole nla larin okuku
Ijoba ti ijoba nba fun
Gbogbo eni ti o mona Jesu ona de o ilekun ogo si o
Gbaragada lo si
Messiah oni joba
Ona ati ilekun
Imole to mo peregede
Oun joba oun joba
Owara ojo bale ogbele ko loro mo o
Jesu joba idande de okun amu ni leru tuka
Ijoba Jesu de o
Ijoba ti o le tan o
Idande ti n fun ni lominira ailopin ni
Atuni sile peregede
Ijoba to joba ka to se ijoba
Ijoba to joba Lori gbogbo ijoba aye
Ijoba ti o ma jo ba lo nigbati ijoba aye ko ni si mo
Ayeraye lo ye mi oo mo wa n don gbirin gbirin
Ba afinju ba wo ja wa n rin gbendeke
Wa n rin gbendeke oo
Gbedenmuke
Iran obun ni pa sio sio woja
Beni mo wi
Jesu joba o
Ijoba ni mo n gben ri
Oun ni mo n ba soro
Oun ti mo oun gbo oun ijoba ni
Oro ti mo oun so oro ijoba ni
Gbogbo ibi ti mo ba fe se mi te ijoba ni mo gba ni be
A ki yo si mi ni po
Ijoba ti mo gba yii oo ijoba ayeraye ododo ni
Te n ba eni to n rin ninu ijoba emi ni
Eeeeehh
Kings and princes
Rule and reigns
Over tribes and some people
They will shine and they will fail
They come and they must go
But there is one who reigns supreme
Over thrones and all kingdoms
Hallelujah Jesus reigns
O n joba Lori aye gbogbo
Hallelujah Jesus reigns
He reigns
He reigns
Hallelujah Jesus reigns
Oun joba Lori aye gbogbo x2
He reigns-oun joba
Oun joba-He reigns
He-reigns Oun joba
Every kneel-gbogbo ekun
Every tongue-gbogbo ahon o
That he is lord-pe oun lo luwa o
He is lord-oun loluwa
He is Lord-Oluwa ni
He’s in charge
Eni to n fe iye ewa wonu ijoba tuntun
Ayeraye iye re ooo
Iye ti ko ni pekun ti kin ku rara
Iye to mi so ni da segun nipa ajinde ee
Olu fisun te porogodo
Ati ri iye
Oun joba o
Oun joba
Aiku re ee
Oun joba
Onijoba to ni joba
Hallelujah
We bow
Oni joba to ni joba
Oni joba to gba joba tan porogodo
Leyin ijoba yii kosi joba mo.