![Jesus Reigns](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/04/11/a120e354835c45349dd908fc5e95998f_464_464.jpg)
Jesus Reigns Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Mo Se Ba - Tope Alabi
...
Mo se iba fun olorun
agbayeeee
Mo se iba fun olorun
to ni ikawo oun gbogbo
Emi juba fun olorun
to da Orun ati aye papo
To lagbara lorii eda gbogbo oo
Mo se iba fun olorun agbaye
Alagbada inaa
Alawo tele orun
Iwo to da orun ati aye papo
To tun lagbara lorii won
…
Eniyan meji
Nbimo kan soso
Okan soso naa
Aa ma lawon loogun gidi
Obi le bimo meji
Kenu won ma ka won rara
You’re mighty olorun
Ti ipa re kaaa gbogbo ayee
Iwo loo tobe
Mo se iba fun olorun
agbayeeee
Iwo nikan naanii
Mo se iba fun olorun
ikawo gbogbo
Enu re ka gbogbo aye
To fi mo isalu orun Baba oo
Mo gbe fun iwo nikan
Olorun gbogbo wa
…
Won fi eniyan je baale
Tenu re o ka aba
Oba nje lori ilu
Ti ilu o de tori e toro
Jinijini ti mu Are wo ti ko roju arare
Aye o mi o
Orun n wariri lorukoo re
Aye o mi o
Mo se iba
Fun olorun agbayeee
Orun n wariri loruko re ni
Idobale lawon agbagba nwa oo
Ite to ga ju lorun ati ayeee
Mo gbe iba fun o
Baba mi dadaaa
………..
Iwo lolorun
Iwo loluwa
Iwo lolorun to pe
oun gbogbo wa
Oro to lase lori
oun gbogbo oo to da o pata
Eni tooo le mu
Kosi ninu ise owo re
O lagbara looriii eda patapata
Eni tooo le muu
Ko si ninu ise owo to da
Iwo gangan lolopa orun oo
Amuni mamaboo loruko re
Iwo nikan lalagbara
Giga Giga Giga Giga Giga Giga
Gegele ninu awon gegele torun
Iponrin aye iponri mi iponri eda
Mo se iba oluda
Nibo loo le yi aye si
Talo to o Talo ju o
To ba pase fun ojo
Koyipada Kabiesi tani o bi o
Olorun eran ara
Agbara re lo se edidi oun gbogbo
Iwo to soku di iye
Eleri ipin
Sababi orun to gbe aye duro wamwam
Olodumare
O ye keda gbogbo beru re
Olorun ogo
Kabiesi o
Iwo too ni emi ati emi inu
Ipilese aye orun wa nikawo ree
Baba o
O ye keda gbogbo beru re
Olodumare
O ye keda ma wariri fun
Alagbara giga
O ye keda ma wariri fun
Iwo to le pa to le ji
O to tan
Sikun aye sikun orun
Ta lo le gba lowo e
Aaa
O ye keda ma wariri fun
Olodumare oo
O ye keda gbogbo beru re
Awimayeun Alagbara julo
O ye keda gbogbo beru re
Iwo tooni emi ati emi inu
Ipilese aye orun wa nikawo re
Alagbara o
O ye keda gbogbo beru re
Olodumare
O ye keda ma wariri fun
Oni ise iyanu
O ye keda ma wariri fun
Iwo tooo lepa tooo leji
Otootan
Sikun ogbon Sikun apaadi
Nbe lowo e
Baba ooo
O ye keda ma wariri fun
Iba re o lodumare
Ogo ma ni fun o.