![Logan Ti O De](https://source.boomplaymusic.com/group1/M03/EB/6D/rBEeMVw-TzKAYEzLAAC5eUqcXh4698.jpg)
Logan Ti O De Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Logan Ti O De - TY Bello & Tope Alabi
...
Emi mo'un ojumi tiri Mo mo'un etimi ti gbo Mo mo'un ojumi tiri Mo mo'un etimi ti gbo Logan to gbo iro ayo re o Mo mo'un aye ma tiwi
Mo mo'un etimi ti gbo
Mo mo'un eniyan ma tiso
Won ti pe wa ni agan ri Bo ya won ti pe o lo'loshi ri Sugbon logan to de o Olugbala l'aye mi leto Sugbon logan to de yi o Olugbala l'aye e leto
Aye to ti daru tele tele oo Logan ti o de Oro ti eniyan ti n fi alufani re Logan ti o de Oro ti ko dara ti a ti so si o Logan ti o de Oruko ti kin se ti e ta ti pe o Logan ti o de Ani logan ti o de o Olugbala, aye e leto Logan ti o de o Olugbala, aye e leto Logan ti jesu de Olugbala, l'aye e leto Ko si oruko ti aye o le peni Won a ma peni l'agan lona gbogbo Bo ba lowo l'owo, agan ni Bo ba bimo o, agan ni Bo ba t'egbe ko d'agba, agan loje Sugbon logan ti o de Sope logan ti o de Ani logan ti o de lesekese Logan ti o de Logan ti o de o Olugbala, laye e leto Logan ti o de Logan ti o de Eni ta pe l'agan e ma so pe Logan ti o de Awon ta ti f'oruko aburu pe nile won yi Logan ti o de Ani logan ti o de o Olugbala, aye mi leto Logan ti o de o Olugbala, laye mi e leto Ani logan ti o de o Aseda, laye mi leto Ani logan ti o de o Olorun o, laye mi leto Irawo owuro, omo mary yo s'inu oro mi Laye mi leto Alagbara ni shilo Lo ba ranti mi si rere Laye mi leto Enu mi wa kun fun erin oo gbogbo Aye mi leto Aye mi gba iyipada otun logan to de Aye mi leto Aye mi ba le to l'ota ba n wo iran mi Aye mi le to Aye mi ba le to l'ota ba n wo iran mi Aye mi le to Ota ka wo ro Enu won gbetan lori ojukan Aye mi le to Logan ti o de o Olugbala, laye mi leto