![Eruretoba](https://source.boomplaymusic.com/group1/M03/EB/6D/rBEeMVw-TzKAYEzLAAC5eUqcXh4698.jpg)
Eruretoba Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Eruretoba - TY Bello & Tope Alabi
...
Piano
Trumpet(Eru re toba oooo
Eru re to ba ooo
Olorun to soro ti ina yo
Eru re to ba)
Eru re toba oooo
Eru re to ba ooo
Oba to soro ti ina yo
Eru re to ba oooo
Eru re toba oooo
Eru re to ba ooo
Olorun to soro ti ina yo
Eru re to ba oooo
Eru reeee tooooooo ba
Eru re tooooooba oooo
Olorun to soro ti ina yo
Eru re to ba
Olorun to soro ti ina yo
Eru re to ba
Iwo to soro ti okun pupa gbe oooo
Eru re to ba
Iwo to soro ti okun pupa la ooo
Eru re to ba
Iwo to soro ti ina yo ooh
Eru re to ba
Iwo to soro ti iiina yo ooo
Eru re to ba
Iwo to fi 'di idin je odidi oba
Eru re to ba
Eru re to ba olorun ooo
Eru re toba ooo
Ah ahah
Iwo to so esteri di ayaba lojiji
Eru re to ba
Omu eru kuro larin eru owa so eru di oba ti gbogbo aye wari fun
Eru re toba
Eru re toooba ooo
Olorun to soro ti ina yooo
Eru re toba
Ahaha olorun to soro ti ina yooo
Eru re to baoooo
Eleda to soro ti ina jade
Eru re toba oo
Omu omi jade ninuapata wa talo dabi re oooo(anahahn)
Eru re toba
Ah
Oseun tenikan ole se ayeraye
Eru re toba
Olorun to soro ti ina yoo
Eru re toba
Olorun to tun aye awa naa se
Eru re toba
Eni ti ati ro pe kole pago wa di eni to kole alaruru ahh
Eru re toba
Aya re to ja iyan ahhh
Aya re to ja iyan olori aye
Eru re to ba ooo
Oh aya re jami ye yeyey
Eru re toba ooo
Ahah ah
Ogo re yi po ohoh
Eru re toba
Eru re to ba ooo
Eru re toba
Eru re toba ooo
Eru re to baooooooo
Eru re to baooo
Eru re toba oooooooo