- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
War - TY Bello & Tope Alabi
...
Instrument
What i hear in my spirit
Edi de togun togun
Edide tija tija
Edide alagbara
Dide olorun mi ko wa se iran wo fokan mi
Dide togun togun
Olori ogun
Akoda ogun
Asaju ogun
Akehin ogun labo
Dide alagbara
Dide oni mole
Dide alagbara
Ko wa se iran wo fokan wa
Awa o mo yin
Oruko melo la mo ta le po
Gbogbo araye iba mo oriki e won ba ma ki o ni gbogbo ojo ni
Alagbara
Asaju ogun lalo
Akehin ogun labo
Pipinikin
Ojijifi
Aji pojo iku da
Opa kan wo kan ye
Ji kan lukan pa
Olowo ori aye
Oni kokoro aye lowo
Eji pota bi ko yingi
Ojo paoke bi koyegere
Beni oke yi osa
Iba re oke tio ye
Iwo nikan loke nlaaass
Arogun matundi ooo
Arabata ribiti
Aribiti rabata
Alejo ti se onile kan ri kese
Onile kaya kajo
Alebe noah sasi
Alabele asa wa
Gbani Gbani lojo oju ogun le
Ogbe omo nija somo daje
Ogbe omo nija somo doso
Kokoro inu aye
Kokoro ode aye
Ilekun
Kokoro ati kogun ati wole Tinu ile tita ode
Kabiyesi olodumare
Pata pata gbogbo gborogodo
Oro godo gauin
Asiri aye
ohun orun
Oro godo gauin
Asiri angeli asiri agbagba merinlelogun
Oro godo gauin
Asiri isale ile asiri ile pepe asiri inu awon ofurufu
Kabiyesi o lo bi owo omi
Okoja owo aso
Owo ju ate ileke lo
Olori aye gbgbo
Olori eda gbogbo
Olori angeli
Oba eniyan
Oba e da gbogbo
Olori awon agbagba merinlelogun
Eda orun won po lo repete
Iwo nikan loga gbogbo won
Emi inu awon woli mimo
Ada tan atobi tan o koja kika
Terere oko ja riri
Gigun lailopin ailetu ooo
Adahun ro adahun so adahun ise
Olu inu awon orun
Oke nla
Kabiyesi ooooooo
Agbe ooooo ga