- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Ayo - TY Bello & Tope Alabi
...
Ayo to kun inu wa
Erin to gba enu wa kan
Agbara toun te wa siwaju
Ogo ye ile re
Ayo to kun inu wa
Erin to gba enu wa kan
Agbara toun te wa siwaju
Ogo ye ile re
Ti ko ba si iwo
Eni araye so lokun mole, talo le tu?
Ti ko ba si iwo
ota a teri wa mole ama rin kaka
Iwo naa ni
Agbara toun te wa si waju
Iyin ye ilere
Ooooooo
Ogo ye eni toh san julo
Ogo ye eni toh dara julo
Ogo ye iwo to dawa laworan re to fayo kun inu wa
Ogo ye ilere
Ota ofe kayo
Iwo lerin toh gba enu wa
Ota ofe kayo
Bi ka te eba ka ma ri obe fi je ni
Iwo lagbara toun te wa siwaju
Daddy ogo ye ilere
Ayo to kun inu wa
Erin to gba enu wa kan
Agbara toun te wa siwaju
Ogo ye ile re
Ota boju wo wa oni taloun ba wa se bawo lase se
Iwo lerin toh kun enu wa
Iwo lagbara toun te wa siwaju
Baba oo
Ogo ye ilere
Won ti bere pe bawo la se sey gan (keyboardist play Ayo to kun inu wa erin to gba enu wa kan agbara toun te wa siwaju ogo ye ile re)
Igba mi ran wa tun sowipe soun nikan ni se oni ori meji
Sugbon okan je ayo wa si be oje erin wa sibe
Osi je agbara toun te wasiju
To ba se ni ti ota
Ero eyin loun fe je ka je
Ooooooo
Ogo ye eni toh san julo
Ogo ye eni toh dara julo
Ogo ye iwo to dawa laworan re to fayo kun inu wa
Ogo ye ilere
Iwo ni ayo toh kun inu wa
Erin to gba enu wa kan
Agabara toun te wa siwaju
Ogo ye ile re
Thank you Lord Jesus.