![Agbara Iku](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/04/C5/rBEeM1f8lfWABXyMAACpdgE_Tr8808.jpg)
Agbara Iku Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:1991
Lyrics
Agbara Iku - Chief (Dr) Sikiru Ayinde Barrister
...
Bi Ku se lagbara to kologun to te leri ti ku se ooo
Biku se lagbara to 2x To sologun to le ri ti ku se
Bola ku se to Olorun Oba ki be ese e wo 2x
All) Bi ku se lagbara to 2x Ogidi Oro ni Bi ku se lagbara to Kologun to le ri ti se ee
To be pe iku pelu Olorun
Tolorun ba binu to be ri ibinu eh oo
Tolorun ba fun ni ru eni
Pe kilode to fi pahun iku Ibati