![Dimensional Fuji](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/04/C7/rBEeMlf8lkGAXOiCAACr-xLmmkA462.jpg)
Dimensional Fuji Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:1993
Lyrics
Dimensional Fuji - Chief (Dr) Sikiru Ayinde Barrister
...
Ayinde Tide Olorin Oba aa, Apede Ara fawon tomonyi o. X2, Olorin Oba Topeleke Afagbon Isale gbodu toloyin Apede Ara fawon tomo Iyi.
2x Toba ti ri Orin Komakinroju, Tobatiri Orin koman mikan, Ayinde o. Ayinde Oba Apede Ara o. Eteti Egbo Labare timogbede t'Omode T'agba to to arere, Apede mapetanan motundeo. Alhaji Agba Motun gbekan yo. Dimension of fuji timogbede. Odile Odu, Odile Orin eniba modu kobami kalóo, Motun tiyi fuji pada o, si new dimension 2x Omokeke njooo, Agbalagba wonjooo 2x, new future njoooo awon Osëre njooo. Awala lalujo opan Oduoo. torin Tilu wa ofa ogbon yo.2x Iyanre Oberee, 2x teko tolele ni agbeo. Bariwonder gbeo ewoju öbe emuyano.2x Isu parade odi Iyan, Agbado parada Odi Eko.