![Ma Se Rere](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/04/C5/rBEeM1f8lfWABXyMAACpdgE_Tr8808.jpg)
Ma Se Rere Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:1991
Lyrics
Ma Se Rere - Chief (Dr) Sikiru Ayinde Barrister
...
Ma she rere l'aye mi, ma she rere (4ce)
Nwo diite l'aye, nwo ni diite l'orun
Nwo ni she baje omo lakeji
Ma she rere l'aye mi, ma she rere
Baye n gbogun e sha ma wuwa re...
...Baye n diite e sha ma wuwa re (2ce)
Aaba f'abo fo n'ise o ti damiloju,
Ise owo eda ni o gba edala
Baye n gbogun e sha ma wuwa reee
Nigeria, which way are we going (2ce)
For military men to rule, our nation at all times,
Politicians, better get together
To practise democracy, in the way it should be done
Let's get together and do things in common
For the benefit of our nation and the incoming generations
Let's think twice, before we move (2ce)
E ma s'ope mo daran enu
Doki mo so yi mo duro
Olooto kii ma yi Leni
****Drums******
T'ori ijo ijo kan hun bo o, ta o jo pade r'ojo
Baba God a dajo oo... eni ba se a wo na
E s'aye re s'aye re (2ce)
Eni aye bakan e s'aye re (2ce)
Oorin n be l'enu Alhaji Agba oo
Ohun n be l'enu Alhaji Agba oo
Aba ni ikan yin da
Awodi to lo s'iba lo redi won s'ebi eye ku
Oro bi lo bi owe (aba ni ikan yin da)
Awodi to lo s'iba lo redi won s'ebi eye ku
Oro bi lo bi owe
Ota ba n lu ilu won jo won n yo
Ota mi mayo mo oo emu reverse
Ayinde o ku o lo gba research
Awodi o ku eye wa laaye
Won she b'orin tan o Orin ku ni ikun mi (3ce)
Eni gbe'yan le gbe'ba
Mo mo pe onitohun o mo nkan
Eni f'adaba we tolotolo (on fi iku we oorun) eetan ni o pa onitohun
Oorin n be l'enu Alhaji Agba oo
Ohun n be l'enu Alhaji Agba oo
Sikiru Ayinde mo de o agbede gbeyo
Music ambassador many potential ni (2ce)
Orin ti wa f'ogbon yo o oye po ni be oo
Awa kii pede ti o ba n'itumo oo
Ti wa yaato si ti worowooto
Ema fi pe ara n ta won ........
Ema f'ori ologini we t'ololaajo
Won jo ra won ni iyato po ni be oo
Mekuturu won kii ko letter
Mekako won kii re cinema oo
Lakriboto won e ba okunrin lo
Awon .......
Lolade mi o ri agbara kan to koja Waheedu
Mi o ti ri agbara kan to koja Waheedu oo
Wala ya sha una illa ya sha Allahu
T'ori pe
Laola W'Allah ku wata (Illa billai illa liliazim) 2ce
Mi o loogun amo mo ni Qur'an
Onje won n'ilorin afonja enu dun juyo oo
Ilu to jin s'ina to sun mo alujaana
On je won l'Epe t'omo alaroo
Ogunmodede Epe l'oni Qur'an oo
On je won n'ilu alfa Iwo omo odo oba
..........
Ha! eni s'oro mi laida
Ko ni ku ko ni run
Ayinde Ogun, ni s'oju emi e nwo b'ori ota oo
Ilu n be l'eyin Alhaji Agba oo
Oni panla subu, o s'ope t'oun baje oo
Nigba t'oni panla subu, to s'ope t'oun baaje oo
Idi oro re janmo, eni to gb'eyin awo ru
To subu pelu eyin e sebi iyen oo gb'ona orun lo ni
Won wa ni k'eran o gbo ooo
Aja ku s'ita e o yo kandu
Epiri bo s'ode o yo fanda
Kiniun f'owoleran o nwo ye gbogbo won
At'epiri at'aja eeran ko ko, eran ko ko, eran ko ko ni gbogbo won
Won s'oro eja t'otobi toburu
Obokun bo s'odo o n yo fanda
Igbakere loun l'oga gbogbo won n'ibu
Kote ni kilo subu te oun oo
Yoyo n'ibo na maa gba pelu shawa
Bi shark o gbe ee
Oro re bi shark o gbe
Akurakuta, akurakuta, akurakuta mi gbogbo won je
Oorin n be l'enu Alhaji Agba oo
Olowo odun kan o je ara'le o gbadun tori ofe pa ileya
Oni ki gbogbo ara'le ki won kuro ladugbo pe olowo fe s'odun
Oode s'agbeje mowo ko je ara'le gbadun
Oo s'odun jeje
Ko te pa mo se e niwoyi odun ...
S'eni to tin p'agbo bo lat'ogun odun seyin
T'owo tun shi n be lowo e kini ko wi na
Koni ki gbogbo ara'ye o ki won f'aye le koun maa da gbaye
Agba to lomi ninun Ayinde olokun ola kii run rara
Eni to yo n panu e ni
Ebi n pa won.... lori asan bansa
Ojo ro ro ro ko i da
Ajeere f'idi kale on f'onu lasan bansa
Ikoko amu .....
Ase t'ojo o ba da l'ogun odun oo
K'ajere wonu odo, ko wonu osa ko wonu okun bo
K'ajere jade si gbangba ...
Se wa renu orofo ni o p'orofo
Ninu eye o ti damiloju
Orofo to b'imo meta ti o j'araye o gbadun
Toni ile oun kun soso
Ee je a ran leti Koledowo ninu film Koto Orun
Koledowo bimo mejo ko j'arale o gbadun
Oun pelu 'yawo e on ko won jo k'aye
Eni to b'imo n dunnu
Eni o l'omo lodeede ti gbogbo won sokun
Awon apapo eye pelu Ogunjimi gbogbo won f'owo l'eran
Won wo'se eni t'aye n ye ton yo laayoju
To gbagbe pe aye fele
Pe t'isu eni ba jina aafowobo je nitori ara'ye
Kope kojina omo mejejo f'aye le Oyiboyi fiwon d'ajo
Eba mi t'aka s'ori sanmori t'ewe t'agba enu wa o ni pawa oo
Eso pele ni t'igbin koje f'obo jawura nitori aye fele
B'eye owiwi ba diju kii ma i s'epe o go...
.....
Efun kii mojo ebibi kan kii d'osu koma la l'aye
Tobato asiko ati su, idi ni lati la oti dami l'oju
B'ewure ba foju weyin a fepe felepe binu eran ba mo
B'aguntan ba boju weyin o a fepe felepe binu eran ba mo
E wa s'ami ki n gbo oo ara ye o ni pawati bii aso to gbo laye
Omo ara'ye o ni ko tiwa nigba ta o ba to s'ebaje araye
Iran tete kii te l'awujo awon efo oti damiloju
Sikiru Ayinde o ni te ninu oloorin ileyi e bami s'amin
Iwaju loju kun gbe nigba taa obati diite m'eni tofe gberi
Adaba n pogede bii pe eyele o gbo
Eyele ku ku gbo oo
Titiri to n tiri kii s'epe koleja oruko lo n sa fun
Nitori pe bibiire iyen o se f'owora lo se n dake
Aso oke kii te nibiti won gbe s'egebyawo nile Yoruba wa
Aso ofi o nite oo ninu ase funra ola