Aare Bolajoko Kadiri Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:1993
Lyrics
Aare Bolajoko Kadiri - Chief (Dr) Sikiru Ayinde Barrister
...
b'ori kan ba sunwan aro'gbao b'ori kan ba sunwan aro'gbaa ( *2 )
ori tio royin ogun ko ni ku
eda tio la'gba eni kan oni dawo nan
Bola Joko aya Kadiri
b'ori kan ba sunwan aro'gbaa
ori tio royin ogun ko ni ku
ori tio la'gba eni kan oni dawo nan
Bola Joko aya Kadiri
b'ori kan ba sunwan aro'gbaa
atoto arere Ayinde balogun
kilo tun gbe do'ode Seriki unwaakaa
isowo elegbe leyin mi eje ka lo gbera
ka re'le alaja Bola Joko Kadiri
iya egbe owo ni seef Manriaman
olori ile iseo Ctn t'ile t'oko
grup of one news ni Nigeria
omon aliaja Anantao
omon ore da'Lapo aluku ni'lu lesha
importer and exporter to r'owo shishe
__________ninu transporter o
Shiman shef esecutif fun gbogbo okun travune
to nbe n'itawabale was as Lagos
saida teria fun gbogbo musulumi
tijania to n'bé ni Nigeria
Rayal adini fun gbogbo Nigeria
metioner wath Islam Soso ayeti
iya sunan fun mumini ile'sa o
she ntoju baba mi sheikh alaj'Abia
Kamarudeeni moi toro emi gungun fun wan o
are obirin fun gbogbo musulumi
united Muslim kansu ni Nigeria
she'nbami toju present general
shef Delolu koya aji Rafiu o
Aja Bola Kadiri maman osupa adini
Ayinde Sikiru Seriki unwaakaa o
maman Mukadamu Aremu Ade mi
agun t'asoolo oga wa aji Razaki
yeye meshup ijesa Land moki yi
umak f'egbe lawarudeeni
soso ayeti ni Nigeria to n'bé n'lu le sha o
iya egbe awan lawarudeeni
lawarudeeni soso ayeti
Bola Kadiri k'ori je o pe l'aye o
gbogbo ewu t'okoja lo ka ma ri ru e man o ebami saami
uunn...
mo l'agogo duro t'Olorun mon gba fun Muhammadu eyobo oni se'nla
omon gbon seni omon Adaman wan gba lu wanyo wan njo
bi'wun to seni oba pa ni
b'oni toun bo gb'Olohun gbo to gba tawakalitu
owun nan yio pada leyin eni ni
oju yo ri oni foo
ode rajo regede lo ri
oju yo ri oni pe ko fo ju seyin i'nla laye_laye
ile aye oni yi ki pa ko oui pada ko k'oju s'iwaju
be l'oju kiifo k'ówó peki bayi pada ko wa sinan enu
ema ku iledeoo
Alaji Adaman l'Agege
sheikh Ilori to f'aye le lojosii
gbogbo marikas eku ara fera ku
musulumi eku ara fera ku
Olorun oba ko f'ori j'oku orun baba wa
Olorun to sei adupe Olorun to sei oseun
oro etan la t'enu ota oti fa'gi le
Olorun to sei adupe Olorun to sei oseun
oro etan la t'enu ota oti di weloo
Olorun to sei adupe o
Mariaman Olorun to sei oseun
oro etan la t'enu ota oti fa'gi le
Olorun to sei adupe Olorun to sei oseun
oro etan la t'enu ota oti di weloo
babaj'aye de aye aman y'ashoun..
ba'osi j'aye de aye aman y'ashoun..
ba gba le gbajo aye aman pe asheun oo
aye aman pe asheun aye aman pe asheun oo (*5)
mo feyi lara mo n'le niyan tetemi ti jee (*2)
me ma shaa sheti l'aye mi oo
ki t'emi odara tetee mi je awa t'emi odara tetee mi je awa (*2)
mokun'le mo gb'onan mo kule f'okomi aa (*2)
oko men l'olori aya mo wule o aa
ki te mi odara mo wule f'oko o aa t'emi odara mo wule f'oko o aa (*2)
ijesha re oo ar'okun yo ijesha re oo ar'okun yo yeshi ogbodo fowo ka omon okun kuya (*2)
nawo nawo man un touwa nawo nawo man un touwa
b'Ola jounbo kii sagba alubrika lounwaa
Mariaman mi ki mai sagba alubrika lounwaa
eyi to n'bé ni le ko ma baje k'aalekun ire kokari (*3)
nawo nawo man un touwa b'Ola nawo nawo man un touwa are nawo nawo man un touwa nawo nawo man un touwa
b'Ola Kadiri ki mai s'agba alubrika lounwaa
eyi to n'bé ni le ko ma bajeo k'aalekun (*2)