![His Faithfulness](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0D/B4/rBEeMVi5a0OAILkjAADc0xMeRgg92.jpeg)
His Faithfulness Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1999
Lyrics
[ti:04 His Faithfulness]
Emi o po okiki re oluwa
Nitori iwo lo gbemi leke
Ti iwo kosi jeki awon ota mi yo mi
Oluwa olorun mi
Emi kigbe pe o
Iwo siti mu mi lara da
O gbami lowo ota mi alagbara
Ati awon tio kori ra mi
Nitori ti won lagbara j mi lo
Won doju ko mi lojo iponju
Oluwa ni alafeyin ti mi
Oluugbala**
Iwo ni ma sin dopin
Olorun mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Mo jewo re
Moti je ileri fun o
Woni nikan owa leyin
Mo fori bale fun
Mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Olorun mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Mo jewo re
Mo ripe o le gba mi
Olorun o l’agbara
Agbara j torisha lo
Mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Olorun mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Mo jewo re
Johi ha hiru
Johi ha hiru
Oluwa ni oba nla
Johi ha hiru
Johi ha hiru
Oluwa ni oba nla
Iwo ni mo ni baba
Mase ja mi kule
Moti diro mo oro re
Mase je kemi kuno
Oh baba
Iwo ni ma sin dopin
Olorun mo jewo re
Iwo ni ma sin dopin
Mo jewo re
Oba ti mo ni ju won lo
O juwon lo
O juwon lo
O juwon lo (x2)
Gbogbo agbara laye
Gbogbo agbara lorun
Oun nikan la fi fun
Oba ti mo ni ju won lo
O juwon lo
O juwon lo
O juwon lo
Atobajaye o mo kio
Oba toni igba yio mo yin o
Arugbo baba agbalagba o
Iwo ni ma sin titi o e
Ere bi apa mi no da o e
Ono ope mi ma to sio baa mi
Iwo to dami si to jeki esu ko gba mi lo
Iwo ni ma fiyin fun o e
Oba ti mo ni ju won lo
O juwon lo
O juwon lo
O juwon lo (x2)
Gbogbo agbara laye
Gbogbo agbara lorun
Oun nikan la fi fun
Oba ti mo ni ju won lo
O juwon lo
O juwon lo
O juwon lo
Baba alagbara iwo ni ma ma yin o
Iwo ni ma ma yin
Baba olutunu iwo ni ma ma pe o
Iwo ni ma ma pe olorun
Baba awimayehun oni majemu nla
Titi aye lemi o ma gbe o ga
Opo jesu ni mo dimu
Ema ni kose re sile iro iro pata
Opo jesu ni mo dimu
Me ma ni kose re sile iro
B’aye gb’ogun b’ota d’ite
Odi dandan ko wa mi ri
Tani ma fi jo t’ota koba damu mi
Tani ma fijo bi nko ba ri idamu ota
Tani nma fi jo t’aye o ba hale mo mi
A tun seyi to jube fun jesu
O sha bori
Baba alagbara iwo ni ma ma yin o
Iwo ni ma ma yin olorun
Baba olutunu iwo ni ma ma pe o
Iwo ni ma ma pe olorun
Baba awimayehun oni majemu nla
Titi aye lemi o ma gbe o ga
E ma wa bami yin o oba alagbara
Oba to gbami lowo iku
To sope ise on po repete
Esu te
Esu te o
Abukun kan satani
Esu te o
Iwo ni ma ma gbe ga o
Olorun igbala mi o
Iwo ni ma ma yin logo
Olorun igbala mi o e
Esu te
Esu te o
Abukun kan satani
Esu te o
Ise mo fowuro se ko ma baje o
Ise mo fosan mi se koma baje
Ise mo fale mi se rere la je o e
Oun mo fowuro se ko ma baje o
Ise mo fosan mi se koma baje
Ise mo fale mi se ere la je o ere
Ise mo fowuro se ko ma baje o
Ise mo fosan mi se koma baje
Ise mo fale mi se rere la je o e
Oun mo fowuro se ko ma baje o
Ise mo fosan mi se koma baje
Ise mo fale mi se ere la je o ere
Oda be
Ogbagba te wa gbami o e
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo aye
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo iku o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo alaroka
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo adeno gbare eni
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo osho
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba gbami lowo aje
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o afi iwo
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o afi iwo
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Iwo nikan lo le gbami o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Iwo nikan lo le se o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o e
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
O gbagba jo wa gbami
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o e
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba
Me ma lenikan mo o
O gbagba
Iwo ni ma sin dopin
O gbagba