![Bi Ose Wu Oluwa Lo'Nsola](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/01/rBEeM1fu0FqASRfwAACp9M_USdc531.jpg)
Bi Ose Wu Oluwa Lo'Nsola Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:01 Bi Ose Wu Oluwa Lo'Nsola]
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola (x2)
Ojo to ro to ro si ireke
Ti ireke ndun ba ba mu s’enu
Ojo oun lo ro to ro si ewuro
Ti ewuro nkoro ba ba mu senu
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Ojo to ro to ro si ireke
Ti ireke ndun ba ba mu s’enu
Ojo oun lo ro to ro si ewuro
Ti ewuro nkoro ba ba mu senu
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Iyawo ile fowo lu ogiri gbigbe
Ala nita iyen fe boyun je
Abi ka bi olorun lere o
Wipe nawo lese pin
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Iyawo ile fowo lu ogiri gbigbe
Ala nita iyen gbero ati boyun je
Emo je a bi olorun lere o
Wipe nawo lese pin
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Awon kan lowo won romo ra loja o
Awon kan bimo won rowo fi to
Sha oni bi olorun lere
Wipe bawo lo se npin
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Olore osan tete ji
Afe mojumo loti jji
Odosan ka to gbere ya fun
Eso fun ko ye se akitiyan
Bo se wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola e
Moni olore osan tete ji
Afe mojumo loti jji
Odosan ka to gbere ya fun
Eso fun ko ye se wahala kiri
Tori bi ose wu oluwa lo n’sola
Bo ba wu ole ni ki agbale oja ma kole
Bo ba wu baba mi e
Ole ni kki baba alaso mati rile ko
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Oshise wa lorun
Onse kira kita lojojumo ni
Awon abanije nyokun
Won gba ategn sara
Awon ashebi ndagba
Loju araye won rise
Awon enire ma nkoja lo o
Die die won pada sodo olorun won
Awa wa nbi olorun lere pe
Baba bawo lose pin
Bi ose wu oluwa lo n’sola
Bi ose wu oluwa lo n’sogo
Ko seni to le bi lere
Bi ose wu oluwa lo n’sola (x6)