![Ojumo Mo/Saanu Mi](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/2A/rBEeMlfx8wqAdKBHAAB2obJ5JLk202.jpg)
Ojumo Mo/Saanu Mi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:01 Ojumo Mo - Saanu Mi]
Ojumo mo o baba mi loke mo yin o
Ojumo oni mo o baba mi loke mo gbe o ga
Ojumo mo o baba mi loke mo yin o
Ojumo oni mo o baba mi loke mo gbe o ga
Mofe ma jade loni
Baba se amono mi
Mofe ma jade loni
Baba sho ishise mi
Ki showo kin bode pade o
Olorun meta lokan
Wa dakun
Wa dakun
Wa bami se (x2)
Wa dakun
Wa dakun
Gboro mi ro baba
Oluwa mo ma njade lo
Oshise ijoba ni mi
K’oko ma ma sha mi o
K’omo araye ma ma koba mi
Kin ma ma se ase danu
Wa dakun
Wa dakun
Wa bami se (x2)
Wa dakun
Wa dakun
Gboro mi ro baba
Ise owo mi ni mo unje edumare wa bami se o
Ise owo mi ni mo unje edumare wa bami se o
Ki irin ise mi ma doju ija ko mi a
Kin ma gbano olorun
Wa dakun
Wa dakun
Wa bami se (x2)
Wa dakun
Wa dakun
Gboro mi ro baba
Oooluwa mi
Saanu mi
Saanu mi (x2)
Iwo ti gbagbe mi pe to
Iwo ti poju re mo pe to kuro lara mi
Emi ti ma gbe okan mi pe to
Tio emi o ma wanu ibanuje ni okan lojojumo
Ota mi oti gberaga sori pe to
Olorun mi oo
Ko kio si gbohun mi
Oluwa
Oluwa
Olorun mi (x2)
Rojo mimo re
Ki o ma sun oro iku
Olorun
Ki ota mi koma ba wipe emi ti segun re
Ki awon ti nya mi lenu maba yo
Olorun nigba ti aba shimi nipo
Sugbon emi gbekele anu re
Okan mi yoyo ninu igbala re
Sugbon emi gbekele anu re
Okan mi yoyo ninu igbala re
Oooluwa mi
Saanu mi
Saanu mi
Oooluwa mi
Saanu mi
Saanu mi
Iwo ti gbagbe mi pe to
Iwo ti poju re mo pe to kuro lara mi (x2)