![The Pledge](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0D/B4/rBEeMVi5a0OAILkjAADc0xMeRgg92.jpeg)
The Pledge Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1999
Lyrics
[ti:02 The Pledge]
Jiiii
Okan mi ji korin
Korin s’olorun re
Ji o
Okan mi ji korin
Ise ati oruko nla oba aye raye
Soti ti iyanu ododo re
Kede agbara re eniyan ko gbo
Korin ileri ore ofe
Ti olorun wa nse (x2)
E ho iho ayo si oluwa eyin ile gbogbo
Ewa ayo sin oluwa
Ewa tie yin ti orin si iwaju re
Ki eyin ki o mope oluwa
Oun ni olorun
Oun ni o da wa
Tie ni awa
Awa ni eniyan ati aguntan papa re
Jiiii
Okan mi ji korin
Ji o
Okan mi ji korin
Ise ati oruko nla oba aye raye
Soti ti iyanu ododo re
Kede agbara re eniyan ko gbo
Korin ileri ore ofe
Ti olorun wa nse
Elo si enu ono re tie yin ti ope
Ati si agbala re tie yin ti iyin
Ema dpe fun
Ki esi ma fi ibukun fun oruko re
Nitori ti oluwa wa po ni ore
Anu re ko ni ipekun o
Ati otito re lati iran di iran ni
Jiiii
Okan mi ji korin
Ji o
Okan mi ji korin
Ise ati oruko nla oba aye raye
Soti ti iyanu ododo re
Kede agbara re eniyan ko gbo
Korin ileri ore ofe
Ti olorun wa nse
Oba aye raye iwo ni iwo ni
Iwo ni
Awimayehun iwo ni iwo ni iwo ni
Iwo ni
Iwo loni mi
Alagbara
Iwo o da mi
Iwo lo fun mi lore ofe
Ti mo fi nse ako
O wa leyin mi
Mio se ni shako
O gbemi ro
Mio se ni shako
Iwo lo nda mi lola
Mio seni shako
Iwo lo npese fun mi
Mio seni shako
Ema dimi mu
E jen shako igbala
Awon ti o gbeke le olorun
Won o dabi oke sioni
Ti ako le shi ni ipo pada lailai o
Ema seun
O wa leyin mi
Mio se ni shako
O gbemi ro
Mio se ni shako
Iwo lo nda mi lola
Mio seni shako
Iwo lo npese fun mi
Mio seni shako
Ema dimi mu
E jen shako igbala
Eni to joko sibi ikoko oga ogo
Ni o ma gbe
Ni o ma gbe
Abe ojiji olodumare o
Baba wa leyin mi oro mi ti dayo
Igba ti moti mo baba loro mi dayo
Igba ti mo di jesu mu loro mi ti dayo
Mo tun ni jesu leyin mi
O o e o o e
O o e o o e
Fi agbara re han mi o
Kemi le ma gbe o ga o
Fi agbara re han mi o
Kemi le ma yin o logo
Agbara mi ko lo fi nse se o
Openishola lo foro mi se iyanu
Agbara mi ko lo fi nse se o
Ore ofe nla ni lo ma fi nse se o
Agbara re nse iyanu
Agbara re lo tumi sile o
Agbara re ngbemi leke o
Agbara re ngbemi ga
Agbara mi ko lo fi nse se o
Openishola o
Openishola o
Openishola ni
Openishola lo foro mi se iyanu
Agbara mi ko lo fi nse se o
Openishola lo foro mi se iyanu
Agbara mi ko lo fi nse se o
Ore re po laye mi lo fi nse se o
Agbara mi ko lo fi nse se o
Openishola lo foro mi se iyanu
Olorun o ma se o
Baba mi o ma sen
Ore ofe nla ni eyi to fi fun mi
Emi ma yin o logo o
Agbara mi ko lo fi nse se o