Intro Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Yeah
My name is Psalm Bee
And I'm welcoming you all,
to the journey of ALUBARIKA
A deeply personal album
that embodies the essence of blessings
Yeah, don't get me wrong
I mean God's blessings
ALUBARIKA isn't just a word
It's a testament to the love,
guidance, and strength that
shapes our various lives
Well, it hold a special significance as it's also the name of my beloved mother who has been my guiding light
Although she has left this sinful world
Her spirit continues to inspire every note and lyrics in this album
ALU-BARIKA (ohhhh)
Tórì b'ádìyé f'ẹsẹ há lẹ, ìré ló n wa
L'owùrọ bi mo ba ji kin r'írè
L'ọsán kin r'írè
L'ójójùmọ
Ójójùmọ àiyé mí, írè ni
Akí torí gbìgbò ká p'ajà
Ìyá ki tòri ìwá l'ile Ọmọ kò p'ọmọ
Atèwè a t'ágbá, iré ni ẹ mọ fí wà mì rí (oh-oh,oh)
Tórì bà bá f'éyìn wàju gìrán, èrìkí à gbá
Ìrán òjú órò ní n lékè òmí
Ìrán óṣibàtá ní lékè ódò
Ó d'ólùlékè ló nì
A kì f'óyín s'ẹnù ká lè jú
Ádùn, Ádùn nì kó wà mí rí
(oh-oh)
N jẹ́ Òrì ẹnì l'áwùré
Òrì ẹnì lò n gbá nì
Òrì lá n fí lá 'bù àiyè já
(oh-oh)
Órì mi má sáigbèmí
(oh-oh)(oh-oh)
ÁLÙBÁRÌKÁ nì mó pè
Áiyè ó ní yẹyẹ ÁLÙBÁRÌKÁ ẹ
(Amin)
Ẹwá Ọlọrùn, Òwó Ọlọrùn á má f'árà hán nìnú áiyè ẹ
(Amin ma)
Gbògbó íbì tó bá dé tó tìn kọrìn
Áwọn aìyé, á t'áwọn tòn gbọ
á t'áwọn rá órìn ẹ
ÁLÙBÁRÌKÁ ó nì jì ná sìwọn
(Amin ma)
Ó nì ṣí lẹ tẹ oh
(Amin ma)
Wọn ó nì ṣì òrìn ẹ gbò
(Amin ma)
Òrì ẹ óní gbàbọdé
Áwọn ólòrin Nigeria, tọn gbókìkí wọn
Áwọn bi Davido, áwọn bi Olamide
Gbògbó wọn ná, íwọ nà wà g'ókè àgbá bì tiwọn
Wá bá wọn pèjọ oh
(Amin)
Gbògbó nnkàn tó bá ṣè ÁLÙBÁRÌKÁ
á mà wọnù iṣẹ̀ (Amin, Jesu)
Òkíkì nlá
Òrúkọ ẹ Psalm Bee, Psalm Bee,
Psalm Bee, Psalm Bee
Òrúkọ ÁLÙBÁRÌKÁ nì o
Kónìbajẹ
(Amin,Jesu)
Jesu Oluwa wa
(Amin)
Ẹ ṣé gán ma