Sleepless Nights Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
(Atẹwọ At'àriwo, f'ọmọ to sàbì)
Lati 19 something, tan tì dá mì s'aiyé
Mò tì mọ p'áiyè ò lé
But me i wan get money
Make i get raba wey go carry weight
See this life (oh)
Everything I do is right (oh)
E fit be wrong or is right (oh)
I just wan flex, make I live life (oh)
Ṣ'órí ní lé àìye
Kò s'ẹni kán, tó mà lè gbárà lè
Keep grinding, cause if you kpai kò kán áìyè
K'èmí ṣà tí rà Motor, kín rà lé
(Kìn dẹ r'àlé)
Ṣ'órí ní lé àìye (oh)
È s'ẹni kán, tó mà lè gbárà
Àrà 'tá wúló gàn jú árà 'lé (oh)
K'émí ṣá tí rà Motor, kín rà lé (oh)
Say if na by sleepless nights
Vigilante for don dey ride car
But why this hustle wrapper tight pà
Why I hustle, Anaslack-ya
Mì o lè slack láyé
Say if na by sleepless nights
Vigilante for don dey drive benz
But why me sef never get benz
Them say I lazy, I no get sense
(Uh-uhh)
You know, I say wetin you wan dey do
In this life, people must to talk (oh)
But, no bother me ṣá jáíyè wó
Kó mà lọ̀ f**k (oh)
Wọn mà s'ọrọ
Awọn àràyé wọn a bá binú
Tò bá s'ọrọ
Awọn àràyé wọn a jà sì hó
Sinù kò tó
Awọn tèmí wọn a bá binú
Them fit f**k you
Awọn tèmí wọn a já ẹ si hóhó
Story (oh) story (oh)
Hmm, wọn poly (oh)
Ọmọ university ninu poly (oh)
Òjú mi n red, mó w'óyin (oh)
See this life (oh)
Everything I do is right (oh)
E fit be wrong or is right (oh)
I just wan flex, make I live life (oh)
Ṣ'órí ní lé àìye
Kò s'ẹni kán, tó mà lè gbárà lè
Keep grinding, cause if you kpai kò kán áìyè
K'èmí ṣà tí rà Motor, kín rà lé
(Kìn dẹ r'àlé)
(Uh-uh,Uh-Uh) (Uh-uh,Uh-Uh)
(Uh-uh,Uh-uh)
(Kìn dẹ r'àlé)
(Uh-uh,Uh-uh) (Uh-Uh,uh-uh)
Ṣ'órí ní lé àìye (oh)
È s'ẹni kán, tó mà lè gbárà
Àrà 'tá wúló gàn jú árà 'lé (oh)
K'émí ṣá tí rà Motor, kín rà lé (oh)
(Soji-ji)